ORIN DAFIDI 131
Àṣírí ìfọ̀kànbalẹ̀ 1 OLUWA, n kò ṣe ìgbéraga, bẹ́ẹ̀ ni ojú mi kò gbé sókè. N ò dáwọ́ lé nǹkan ńláńlá, n ò sì dá àrà tí ó jù mí…
Àṣírí ìfọ̀kànbalẹ̀ 1 OLUWA, n kò ṣe ìgbéraga, bẹ́ẹ̀ ni ojú mi kò gbé sókè. N ò dáwọ́ lé nǹkan ńláńlá, n ò sì dá àrà tí ó jù mí…
Majẹmu Ọlọrun pẹlu Ìdílé Dafidi 1 OLUWA, ranti gbogbo ìyà tí Dafidi fara dà. 2 Ranti bí ó ṣe búra fún OLUWA, tí ó sì jẹ́jẹ̀ẹ́ fún ìwọ Alágbára, Ọlọrun…
Ìrẹ́pọ̀ Àwọn ará 1 Ó dára, ó sì dùn pupọ, bí àwọn ará bá ń gbé pọ̀ ní ìrẹ́pọ̀. 2 Ó dàbí òróró iyebíye tí a dà síni lórí, tí…
Ẹ yin OLUWA 1 Ẹ wá, ẹ yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ń sìn ín ninu ilé rẹ̀ lóru. 2 Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè, kí…
Orin Ìyìn 1 Ẹ yin OLUWA. Ẹ yin orúkọ OLUWA; ẹ yìn ín, ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀, 2 ẹ̀yin tí ẹ̀ ń jọ́sìn ninu ilé OLUWA, tí ẹ wà ní àgbàlá…
Orin Ọpẹ́ 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun tí ó ju…
Àwọn Ọmọ Israẹli Kọrin Arò ní Ìgbèkùn 1 Lẹ́bàá odò Babiloni ni a jókòó, tí a sọkún, nígbà tí a ranti Sioni. 2 Lára igi wilo níbẹ̀ ni a fi…
Adura Ọpẹ́ 1 N óo máa yìn ọ́ tọkàntọkàn OLUWA, lójú àwọn oriṣa ni n óo máa kọrin ìyìn sí ọ. 2 Ní ìtẹríba, n óo kọjú sí ìhà tẹmpili…
Ọlọrun Olùmọ̀ràn Ọkàn 1 OLUWA, o ti yẹ̀ mí wò, o sì mọ̀ mí. 2 O mọ ìgbà tí mo jókòó, ati ìgbà tí mo dìde; o mọ èrò ọkàn…
Adura Ààbò 1 OLUWA, gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi; dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá; 2 àwọn tí ó ń pète ibi lọ́kàn wọn, tí wọ́n sì ń…