ORIN DAFIDI 141
Adura Ààbò 1 OLUWA, mo ké pè ọ́, tètè wá dá mi lóhùn, tẹ́tí sí ohùn mi nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́. 2 Jẹ́ kí adura mi…
Adura Ààbò 1 OLUWA, mo ké pè ọ́, tètè wá dá mi lóhùn, tẹ́tí sí ohùn mi nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́. 2 Jẹ́ kí adura mi…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Mo ké pe OLUWA, mo gbé ohùn ẹ̀bẹ̀ sókè sí i. 2 Mo tú ẹ̀dùn ọkàn mi palẹ̀ níwájú rẹ̀, mo sọ ìṣòro mi fún un. 3…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 OLUWA, gbọ́ adura mi; fetí sí ẹ̀bẹ̀ mi! Dá mi lóhùn ninu òtítọ́ ati òdodo rẹ. 2 Má dá èmi ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ lẹ́jọ́, nítorí pé kò sí…
Ọpẹ́ fún Ìṣẹ́gun 1 Ìyìn ni fún OLUWA, àpáta mi, ẹni tí ó kọ́ mi ní ìjà jíjà, tí ó kọ́ mi ní iṣẹ́ ogun. 2 Òun ni àpáta mi,…
Orin Ìyìn 1 Èmi óo gbé ọ ga, Ọlọrun mi, Ọba mi, n óo máa yin orúkọ rẹ lae ati laelae. 2 Lojoojumọ ni n óo máa yìn ọ́, tí…
Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi. 2 N óo máa yin OLUWA níwọ̀n ìgbà tí mo wà láyé; n óo máa kọrin ìyìn sí Ọlọrun…
Ọlọrun Alágbára 1 Ẹ yin OLUWA! Nítorí tí ó dára láti máa kọ orin ìyìn sí Ọlọrun wa; nítorí olóore ni, orin ìyìn sì yẹ ẹ́. 2 OLUWA ní ń…
Kí gbogbo ẹ̀dá Yin OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin OLUWA, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run, ẹ yìn ín lókè ọ̀run. 2 Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin angẹli rẹ̀; ẹ yìn…
Orin Ìyìn sí OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́. 2 Kí Israẹli máa yọ̀ ninu Ẹlẹ́dàá…
Ẹ yin OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀; ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára. 2 Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá…