ORIN DAFIDI 31

Adura Igbẹkẹle Ọlọrun 1 OLUWA, ìwọ ni mo sá di, má jẹ́ kí ojú tì mí lae; gbà mí, nítorí olóòótọ́ ni ọ́. 2 Dẹ etí sí mi, yára gbà…

ORIN DAFIDI 32

Ìjẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí a dárí ìrékọjá rẹ̀ jì, tí a bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀. 2 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí OLUWA kò ka…

ORIN DAFIDI 33

Orin Ìyìn 1 Ẹ máa yọ̀ ninu OLUWA, ẹ̀yin olódodo! Yíyin OLUWA ni ó yẹ ẹ̀yin olóòótọ́. 2 Ẹ fi gòjé yin OLUWA, ẹ fi hapu olókùn mẹ́wàá kọ orin…

ORIN DAFIDI 34

Ẹ yin Ọlọrun nítorí Oore Rẹ̀ 1 N óo máa yin OLUWA ní gbogbo ìgbà; ìyìn rẹ̀ yóo máa wà ní ẹnu mi nígbà gbogbo. 2 OLUWA ni èmi óo…

ORIN DAFIDI 35

Adura ìrànlọ́wọ́ 1 OLUWA, gbógun ti àwọn tí ń gbógun tì mí; gbé ìjà ko àwọn tí ń bá mi jà! 2 Gbá asà ati apata mú, dìde, kí o…

ORIN DAFIDI 36

Ìwà ìkà 1 Ẹ̀ṣẹ̀ ń gbin lọ́kàn eniyan burúkú, kò sí ìbẹ̀rù Ọlọrun ninu èrò tirẹ̀. 2 Nítorí pé lọ́kàn rẹ̀ a máa pọ́n ara rẹ̀, pé kò sí ẹni…

ORIN DAFIDI 37

Ìgbẹ̀yìn Àwọn Eniyan Burúkú 1 Má gbé ara rẹ lọ́kàn gbóná nítorí àwọn eniyan burúkú; má sì jowú àwọn aṣebi; 2 nítorí pé kíákíá ni wọn yóo gbẹ bí i…

ORIN DAFIDI 38

Adura Ẹni tí Ìyà ń Jẹ 1 OLUWA, má fi ibinu bá mi wí! Má sì fi ìrúnú jẹ mí níyà! 2 Nítorí pé ọfà rẹ ti wọ̀ mí lára,…

ORIN DAFIDI 39

Ìráhùn Ẹni tí Ìyà ń Jẹ 1 Mo ní, “Èmi óo máa ṣọ́ra, kí n má baà fi ahọ́n mi dẹ́ṣẹ̀; n óo kó ẹnu mi ní ìjánu, níwọ̀n ìgbà…

ORIN DAFIDI 40

Orin ìyìn 1 Sùúrù ni mo fi dúró de OLUWA, ó dẹ etí sí mi, ó sì gbọ́ igbe mi. 2 Ó fà mí jáde láti inú ọ̀gbun ìparun, láti…