ORIN DAFIDI 41

Adura Ẹni tí ń Ṣàìsàn 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ń ro ti àwọn aláìní: OLUWA yóo gbà á ní ọjọ́ ìpọ́njú. 2 OLUWA yóo máa ṣọ́ ọ,…

ORIN DAFIDI 42

Adura Ẹni tí A Lé ní Ìlú 1 Bí ọkàn àgbọ̀nrín tií máa fà sí odò tí omi rẹ̀ tutù, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mi ń fà sí ọ, Ọlọrun. 2…

ORIN DAFIDI 43

Adura Ẹni tí A Lé ní Ìlú 1 Dá mi láre, Ọlọrun, kí o sì gbèjà mi, lọ́dọ̀ àwọn tí kò mọ̀ Ọ́; gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn ati alaiṣootọ….

ORIN DAFIDI 44

Adura Ààbò 1 Ọlọrun, a ti fi etí wa gbọ́, àwọn baba wa sì ti sọ fún wa, nípa àwọn ohun tí o ṣe nígbà ayé wọn, àní, ní ayé…

ORIN DAFIDI 45

Orin Igbeyawo Ọmọ Ọba 1 Èrò rere kan ń gbé mi lọ́kàn, mò ń kọ orin mi fún ọba ahọ́n mi dàbí gègé akọ̀wé tó mọṣẹ́. 2 Ìwọ ni o…

ORIN DAFIDI 46

Ọlọrun Wà pẹlu Wa 1 Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa, olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú. 2 Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí…

ORIN DAFIDI 47

Ọba Àwọn Ọba 1 Ẹ pàtẹ́wọ́, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ kọ orin ayọ̀, ẹ hó sí Ọlọrun. 2 Nítorí pé ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ ni OLUWA, Ọ̀gá Ògo, Ọba ńlá lórí gbogbo…

ORIN DAFIDI 48

OLUWA Tóbi 1 OLUWA tóbi, ó sì yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọ ní ìlú Ọlọrun wa. 2 Òkè mímọ́ rẹ̀, tí ó ga, tí ó sì lẹ́wà, ni…

ORIN DAFIDI 49

Ìwà Òmùgọ̀ ni Igbẹkẹle Ọrọ̀ 1 Ẹ gbọ́, gbogbo orílẹ̀-èdè! Ẹ dẹtí sílẹ̀, gbogbo aráyé, 2 ati mẹ̀kúnnù àtọlọ́lá, àtolówó ati talaka! 3 Ẹnu mi yóo sọ̀rọ̀ ọgbọ́n; àṣàrò ọkàn…

ORIN DAFIDI 50

Ìsìn Tòótọ́ 1 OLUWA, Ọlọrun Alágbára ti sọ̀rọ̀: ó ké sí gbogbo ayé láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ oòrùn. 2 Ọlọrun yọ bí ọjọ́ láti Sioni, ìlú tó dára,…