ORIN DAFIDI 71

Adura Àgbàlagbà kan 1 OLUWA, ìwọ ni mo sá di; má jẹ́ kí ojú ó tì mí laelae! 2 Gbà mí, kí o sì yọ mí nítorí òdodo rẹ; tẹ́tí…

ORIN DAFIDI 72

Adura Ọba 1 Ọlọrun, gbé ìlànà òtítọ́ rẹ lé ọba lọ́wọ́; kọ́ ọmọ ọba ní ọ̀nà òdodo rẹ. 2 Kí ó lè máa fi òdodo ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan rẹ,…

ORIN DAFIDI 73

Ìdájọ́ Òdodo Ọlọrun 1 Nítòótọ́ Ọlọrun ṣeun fún Israẹli, ó ṣeun fún àwọn tí ọkàn wọn mọ́. 2 Ṣugbọn, ní tèmi, mo fẹ́rẹ̀ yọ̀ ṣubú, ẹsẹ̀ mi fẹ́rẹ̀ tàsé. 3…

ORIN DAFIDI 74

Ranti Wa, OLUWA 1 Ọlọrun, kí ló dé tí o fi ta wá nù títí ayé? Kí ló dé tí inú rẹ fi ń ru sí àwa aguntan pápá rẹ?…

ORIN DAFIDI 75

Ọlọrun Onídàájọ́ 1 A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Ọlọrun; a dúpẹ́. À ń kéde orúkọ rẹ, a sì ń ròyìn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe. 2 OLUWA ní, “Nígbà tí àkókò…

ORIN DAFIDI 76

Ọlọrun Ajàṣẹ́gun 1 Àwọn ará Juda mọ Ọlọrun, orúkọ rẹ̀ sì lọ́wọ̀ ní Israẹli. 2 Ilé rẹ̀ wà ní Salẹmu, ibùgbé rẹ̀ wà ní Sioni. 3 Níbẹ̀ ni ó ti…

ORIN DAFIDI 77

Ìtùnú ní Àkókò Ìpọ́njú 1 Mo ké pe Ọlọrun fún ìrànlọ́wọ́, mo kígbe pe Ọlọrun kí ó lè gbọ́ tèmi. 2 Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA; ní òru,…

ORIN DAFIDI 78

Ọlọrun ati Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Ẹ̀yin eniyan mi, ẹ dẹtí sí ẹ̀kọ́ mi; ẹ tẹ́tí si ọ̀rọ̀ ẹnu mi. 2 N óo la ẹnu mi tòwe-tòwe; n óo fa…

ORIN DAFIDI 79

Adura Ìdáǹdè Orílẹ̀-Èdè 1 Ọlọrun, àwọn orílẹ̀-èdè abọ̀rìṣà ti wọ inú ilẹ̀ ìní rẹ; wọ́n ti ba ilé mímọ́ rẹ jẹ́; wọ́n sì ti sọ Jerusalẹmu di ahoro. 2 Wọ́n…

ORIN DAFIDI 80

Fi Ojurere Wò Wá 1 Dẹtí sílẹ̀, ìwọ olùṣọ́-aguntan Israẹli, Ìwọ tí ò ń tọ́jú àwọn ọmọ Josẹfu bí agbo ẹran. Ìwọ tí o gúnwà láàrin àwọn kerubu, yọ bí…