ORIN DAFIDI 81

Orin fún Àkókò Àsè 1 Ẹ kọ orin sókè sí Ọlọrun, agbára wa; ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun Jakọbu. 2 Ẹ dárin, ẹ lu samba, ẹ ta hapu dídùn…

ORIN DAFIDI 82

Ọlọrun, Ọba Àwọn Ọba 1 Ọlọrun ti jókòó ní ààyè rẹ̀ ninu ìgbìmọ̀ ọ̀run; ó sì ń ṣe ìdájọ́ láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run: 2 “Yóo ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin…

ORIN DAFIDI 83

Adura Ìṣẹ́gun 1 Ọlọrun, má dákẹ́; má wòran; Ọlọrun má dúró jẹ́ẹ́! 2 Wò ó! Àwọn ọ̀tá rẹ ń ṣọ̀tẹ̀ sí ọ; àwọn tí ó kórìíra rẹ sì ń yájú…

ORIN DAFIDI 84

Ṣíṣàárò Ilé Ọlọrun 1 Ibùgbé rẹ lẹ́wà pupọ, OLUWA àwọn ọmọ ogun, 2 ọkàn àgbàlá tẹmpili OLUWA ń fà mí, àárò rẹ̀ ń sọ mí; tọkàn-tara ni mo fi ń…

ORIN DAFIDI 85

Adura Ire Orílẹ̀-Èdè 1 OLUWA, o fi ojurere wo ilẹ̀ rẹ; o dá ire Jakọbu pada. 2 O dárí àìdára àwọn eniyan rẹ jì wọ́n; o sì bo gbogbo ẹ̀ṣẹ̀…

ORIN DAFIDI 86

Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Tẹ́tí sí mi OLUWA, kí o sì gbọ́ adura mi, nítorí òtòṣì ati aláìní ni mí. 2 Dá ẹ̀mí mi sí nítorí olùfọkànsìn ni mí; gba èmi…

ORIN DAFIDI 87

Ìyìn Sioni 1 Ní orí òkè mímọ́ ni ìlú tí OLUWA tẹ̀dó wà. 2 OLUWA fẹ́ràn ẹnubodè Sioni ju gbogbo ìlú yòókù lọ ní ilẹ̀ Jakọbu. 3 Ọpọlọpọ nǹkan tó…

ORIN DAFIDI 88

Adura nígbà ìpọ́njú 1 OLUWA, Ọlọrun, Olùgbàlà mi, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ ní ọ̀sán; mo ké níwájú rẹ ní òru. 2 Jẹ́ kí adura mi dé ọ̀dọ̀ rẹ;…

ORIN DAFIDI 89

Majẹmu Ọlọrun pẹlu Dafidi 1 OLUWA, n óo máa kọrin ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ títí lae; n óo máa fi ẹnu mi kéde òtítọ́ rẹ láti ìran dé…

ORIN DAFIDI 90

Ibi tí Agbára Ẹ̀dá Mọ 1 OLUWA, ìwọ ni o ti jẹ́ ibi ààbò wa láti ìrandíran. 2 Kí o tó dá àwọn òkè, ati kí o tó dá ilẹ̀…