PETERU KINNI 1

1 Èmi Peteru, aposteli Jesu Kristi ni mò ń kọ ìwé yìí sí ẹ̀yin tí ẹ fọ́n káàkiri àwọn ìlú àjèjì bíi Pọntu, Galatia, Kapadokia, Esia ati Bitinia. 2 Ẹ̀yin…

PETERU KINNI 2

Òkúta Ààyè ati Orílẹ̀-Èdè Mímọ́ 1 Nítorí náà, ẹ pa gbogbo ìwà ibi tì, ati ọgbọ́n ẹ̀wẹ́, àgàbàgebè, owú jíjẹ ati ọ̀rọ̀ àbùkù. 2 Ẹ ṣe bí ọmọ-ọwọ́ tí a…

PETERU KINNI 3

Ọ̀rọ̀ fún Àwọn Ọkọ ati Aya 1 Bákan náà ni kí ẹ̀yin aya máa bọ̀wọ̀ fún àwọn ọkọ yín. Ìdí rẹ̀ ni pé bí a bá rí ninu àwọn ọkọ…

PETERU KINNI 4

Ìríjú Rere 1 Nítorí náà, níwọ̀n ìgbà tí Kristi ti jìyà ninu ara, kí ẹ̀yin náà di ọkàn yín ní àmùrè láti ṣe bẹ́ẹ̀. Nítorí ẹni tí ó bá jìyà…

PETERU KINNI 5

Bíbọ́ Agbo Aguntan Ọlọrun 1 Nítorí náà, mo bẹ àwọn àgbà láàrin yín, alàgbà ni èmi náà, ati ẹlẹ́rìí ìyà Kristi, n óo sì ní ìpín ninu ògo tí yóo…