ROMU 1

Ìkíni 1 Èmi Paulu, iranṣẹ Kristi Jesu, ni mò ń kọ ìwé yìí. Ọlọrun pè mí, ó fi mí ṣe òjíṣẹ́, ó sì yà mí sọ́tọ̀ láti máa waasu ìyìn…

ROMU 2

Ìdájọ́ Òdodo Tí Ọlọrun Ṣe 1 Kò sí àwáwí kankan fún ọ, ìwọ tí ò ń dá ẹlòmíràn lẹ́jọ́, ẹnikẹ́ni tí ó wù kí ó jẹ́. Nǹkan gan-an tí ò…

ROMU 3

1 Ọ̀nà wo wá ni àwọn Juu fi sàn ju àwọn orílẹ̀-èdè yòókù lọ? Kí ni anfaani ìkọlà? 2 Ó pọ̀ pupọ ní oríṣìíríṣìí ọ̀nà. Ekinni, àwọn Juu ni Ọlọrun…

ROMU 4

Àpẹẹrẹ Abrahamu 1 Kí ni kí á wí nípa Abrahamu baba-ńlá wa nípa ti ara? Kí ni ìrírí rẹ̀? 2 Bí ó bá jẹ́ pé nítorí ohun tí ó ṣe…

ROMU 5

Àyọrísí Ìdáláre 1 Níwọ̀n ìgbà tí a ti dá wa láre nítorí pé a gba Ọlọrun gbọ́, kò sí ìjà mọ́ láàrin àwa ati Ọlọrun: Jesu Kristi Oluwa wa ti…

ROMU 6

Ikú sí Ẹ̀ṣẹ̀, Ìyè ninu Kristi 1 Kí ni kí á wí nígbà náà? Ṣé kí a túbọ̀ máa dẹ́ṣẹ̀ kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun lè máa pọ̀ sí i? 2 Kí…

ROMU 7

Àpẹẹrẹ láti inú Igbeyawo 1 Ẹ̀yin ará mi, ohun tí mò ń wí yìí kò ṣe àjèjì si yín (nítorí ẹ̀yin náà mọ òfin), pé òfin de eniyan níwọ̀n ìgbà…

ROMU 8

Ìgbésí-Ayé Onigbagbọ ninu Ẹ̀mí 1 Nisinsinyii, kò sí ìdálẹ́bi kan mọ́ fún àwọn tí ó wà ní ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu. 2 Ìdí ni pé, agbára Ẹ̀mí, tí ó ń…

ROMU 9

Ọlọrun Yan Israẹli 1 Òtítọ́ ni ohun tí mò ń sọ yìí; n kò purọ́, nítorí Kristi ni ó ni mí. Ọkàn mi tí Ẹ̀mí ń darí sì jẹ́ mi…

ROMU 10

1 Ẹ̀yin ará mi, ìfẹ́ ọkàn mi, ati ẹ̀bẹ̀ mi sí Ọlọrun fún àwọn Juu, àwọn eniyan mi ni pé kí á gbà wọ́n là. 2 Nítorí mo jẹ́rìí wọn…