RUTU 1

Elimeleki ati Ìdílé Rẹ̀ Lọ láti Máa Gbé ní Ilẹ̀ Moabu 1 Ní àkókò tí àwọn adájọ́ ń ṣe olórí ní ilẹ̀ Israẹli, ìyàn ńlá kan mú ní ilẹ̀ náà….

RUTU 2

Rutu Ṣiṣẹ́ ninu Oko Boasi 1 Ní àkókò yìí, ọkunrin ọlọ́rọ̀ kan wà ninu ìdílé Elimeleki, ẹbí kan náà ni ọkunrin yìí ati ọkọ Naomi. Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Boasi….

RUTU 3

Rutu rí Ọkọ Fẹ́ 1 Lẹ́yìn náà, Naomi pe Rutu, ó ní, “Ọmọ mi, ó tó àkókò láti wá ọkọ fún ọ, kí ó lè dára fún ọ. 2 Ṣé…

RUTU 4

Boasi Ṣú Rutu Lópó 1 Boasi bá lọ sí ẹnu ibodè ìlú, ó jókòó níbẹ̀. Bí ìbátan ọkọ Rutu tí ó súnmọ́ ọn, tí Boasi sọ nípa rẹ̀ ti ń…