SAKARAYA 11

Ìṣubú Àwọn Aninilára 1 Ṣílẹ̀kùn rẹ, ìwọ ilẹ̀ Lẹbanoni kí iná lè jó àwọn igi kedari rẹ! 2 Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, ẹ̀yin igi Sipirẹsi, nítorí igi kedari ti ṣubú, àwọn…

SAKARAYA 12

Ìlérí ìdáǹdè fún Jerusalẹmu 1 Iṣẹ́ tí OLUWA rán sí Israẹli nìyí, OLUWA tí ó ta ọ̀run bí aṣọ, tí ó dá ayé, tí ó sì dá ẹ̀mí sinu eniyan,…

SAKARAYA 13

1 OLUWA ní, “Nígbà tó bá yá, orísun omi kan yóo ṣí sílẹ̀ fún ilé Dafidi, ati fún àwọn ará Jerusalẹmu láti wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ ati ìwà…

SAKARAYA 14

Jerusalẹmu ati Àwọn Orílẹ̀-Èdè 1 Wò ó! Ọjọ́ OLUWA ń bọ̀ tí wọn yóo pín àwọn ìkógun tí wọ́n kó ní ilẹ̀ Jerusalẹmu lójú yín. 2 Nítorí n óo kó…