SAMUẸLI KEJI 21

Wọ́n Pa Àwọn Ọmọ Ọmọ Saulu 1 Ní àkókò ìjọba Dafidi, ìyàn ńlá kan mú, fún odidi ọdún mẹta. Dafidi bá lọ wádìí ọ̀rọ̀ náà lọ́dọ̀ OLUWA. OLUWA sì dáhùn…

SAMUẸLI KEJI 22

Orin Ìṣẹ́gun Tí Dafidi Kọ 1 Nígbà tí OLUWA gba Dafidi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ati lọ́wọ́ Saulu, Dafidi kọ orin yìí sí OLUWA pé: 2 “OLUWA ni àpáta…

SAMUẸLI KEJI 23

Ọ̀rọ̀ Ìkẹyìn Dafidi 1 Ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dafidi nìyí; àní, ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ Dafidi, ọmọ Jese, tí a gbé ga ní Israẹli, ẹni àmì òróró Ọlọrun Jakọbu, olórin dídùn ní Israẹli: 2…

SAMUẸLI KEJI 24

Dafidi Ka Àwọn Eniyan Israẹli 1 Inú tún bí OLUWA sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì ti Dafidi láti kó ìyọnu bá wọn. OLUWA wí fún un pé, lọ ka…