SAMUẸLI KINNI 21

Dafidi Sá fún Saulu 1 Dafidi lọ sọ́dọ̀ Ahimeleki alufaa, ní Nobu. Ahimeleki sì jáde pẹlu ìbẹ̀rù láti pàdé rẹ̀, ó sì bi í pé, “Ṣé kò sí nǹkan tí…

SAMUẸLI KINNI 22

Saulu Pa Àwọn Alufaa 1 Dafidi sá kúrò ní ìlú Gati, lọ sinu ihò òkúta kan lẹ́bàá Adulamu. Nígbà tí àwọn arakunrin rẹ̀ ati ìdílé baba rẹ̀ gbọ́, wọ́n wá…

SAMUẸLI KINNI 23

Dafidi Gba Ìlú Keila Sílẹ̀ 1 Nígbà tí Dafidi gbọ́ pé àwọn ará Filistia ń gbógun ti àwọn ará Keila, wọ́n sì ń jí ọkà wọn kó ní ibi ìpakà,…

SAMUẸLI KINNI 24

Dafidi Dá Ẹ̀mí Saulu Sí 1 Nígbà tí Saulu bá àwọn ará Filistia jagun tán, wọ́n sọ fún un pé Dafidi wà ní aṣálẹ̀ Engedi. 2 Saulu mú ẹgbẹẹdogun (3,000)…

SAMUẸLI KINNI 25

Ikú Samuẹli 1 Nígbà tí Samuẹli kú, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli kó ara wọn jọ láti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀. Wọ́n sì sin òkú rẹ̀ sí ilé rẹ̀ ní Rama. Dafidi ati…

SAMUẸLI KINNI 26

Dafidi Dá Ẹ̀mí Saulu sí lẹẹkeji 1 Àwọn ọkunrin kan, ará Sifi lọ sọ fún Saulu ní Gibea pé, “Dafidi farapamọ́ sí òkè Hakila tí ó wà ní apá ìlà…

SAMUẸLI KINNI 27

Dafidi láàrin Àwọn Ará Filistia 1 Dafidi rò ní ọkàn rẹ̀ pé Saulu yóo pa òun ní ọjọ́ kan, nítorí náà ohun tí ó dára jù ni kí òun sá…

SAMUẸLI KINNI 28

1 Nígbà tí ó ṣe, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti bá Israẹli jagun. Akiṣi sọ fún Dafidi pé, “Ìwọ ati àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ…

SAMUẸLI KINNI 29

Àwọn Ará Filistia Kọ Dafidi 1 Àwọn ará Filistia kó gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn jọ sí Afeki, àwọn ọmọ ogun Israẹli sì pa ibùdó sí etí orísun omi tí…

SAMUẸLI KINNI 30

Dafidi Bá Àwọn Ará Amaleki Jagun 1 Nígbà tí Dafidi ati àwọn ọkunrin rẹ̀ pada dé Sikilagi ní ọjọ́ kẹta, wọ́n rí i pé àwọn ará Amaleki ti gbógun ti…