LUKU 18

Òwe Nípa Opó Kan ati Adájọ́ 1 Jesu pa òwe kan fún wọn láti kọ́ wọn pé eniyan gbọdọ̀ máa gbadura nígbà gbogbo, láì ṣàárẹ̀. 2 Ó ní, “Adájọ́ kan…

LUKU 19

Jesu ati Sakiu 1 Nígbà tí Jesu dé Jẹriko, ó ń la ìlú náà kọjá. 2 Ọkunrin kan wà tí ó ń jẹ́ Sakiu. Òun ni olórí agbowó-odè níbẹ̀. Ó…

LUKU 20

Ìbéèrè Nípa Àṣẹ Tí Jesu Ń Lò 1 Ní ọjọ́ kan, bí Jesu ti ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́ ninu Tẹmpili, tí ó ń waasu ìyìn rere fún wọn, àwọn…

LUKU 21

Ọrẹ Tí Opó Kan Ṣe 1 Bí Jesu ti gbé ojú sókè ó rí àwọn ọlọ́rọ̀ bí wọ́n ti ń dá owó ọrẹ wọn sinu àpótí ìṣúra. 2 Ó wá…

LUKU 22

Àwọn Juu Dìtẹ̀ láti Pa Jesu 1 Ó fẹ́rẹ̀ tó àkókò Àjọ̀dún Àìwúkàrà tí à ń pè ní Àjọ̀dún Ìrékọjá. 2 Àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin ń wá ọ̀nà…

LUKU 23

Wọ́n Fa Jesu Lọ Siwaju Pilatu 1 Ni gbogbo àwùjọ bá dìde, wọ́n fa Jesu lọ sọ́dọ̀ Pilatu. 2 Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí fi ẹ̀sùn kàn án pé, “A rí…

LUKU 24

Ajinde Jesu 1 Ní kutukutu òwúrọ̀ ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, wọ́n wá sí ibojì, wọ́n mú òróró olóòórùn dídùn tí wọ́n ti tọ́jú lọ́wọ́. 2 Wọ́n rí i pé wọ́n ti…

JOHANU 1

Ọlọrun di Eniyan 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, kí á tó dá ayé, ni Ọ̀rọ̀ ti wà, Ọ̀rọ̀ wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun sì ni Ọ̀rọ̀ náà. 2 Òun ni ó wà pẹlu…

JOHANU 2

Jesu Lọ sí Ibi Igbeyawo Kan ní Kana 1 Ní ọjọ́ kẹta, wọ́n ń ṣe igbeyawo kan ní Kana, ìlú kan ní Galili. Ìyá Jesu wà níbẹ̀. 2 Wọ́n pe…

JOHANU 3

Jesu ati Nikodemu 1 Ọkunrin kan wà ninu àwọn Farisi tí ń jẹ́ Nikodemu. Ó jẹ́ ọ̀kan ninu ìgbìmọ̀ àwọn Juu. 2 Ọkunrin yìí fi òru bojú lọ sọ́dọ̀ Jesu….