JOHANU 14
Jesu Ni Ọ̀nà Dé Ọ̀dọ̀ Baba 1 “Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú. Ẹ gba Ọlọrun gbọ́, kí ẹ sì gba èmi náà gbọ́. 2 Yàrá pupọ ni…
Jesu Ni Ọ̀nà Dé Ọ̀dọ̀ Baba 1 “Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú. Ẹ gba Ọlọrun gbọ́, kí ẹ sì gba èmi náà gbọ́. 2 Yàrá pupọ ni…
Jesu Ni Igi Àjàrà 1 “Èmi ni àjàrà tòótọ́. Baba mi ni àgbẹ̀ tí ń mójútó ọgbà àjàrà. 2 Gígé ni yóo gé gbogbo ẹ̀ka ara mi tí kò bá…
1 “Mo sọ gbogbo nǹkan yìí fun yín kí igbagbọ yín má baà yẹ̀. 2 Wọn yóo le yín jáde kúrò ninu ilé ìpàdé wọn. Èyí nìkan kọ́, àkókò ń…
Adura Jesu 1 Lẹ́yìn tí Jesu ti sọ ọ̀rọ̀ wọnyi tán, ó gbé ojú sókè ọ̀run, ó ní, “Baba, àkókò náà dé! Jẹ́ kí ògo rẹ hàn lára Ọmọ, kí…
Àwọn Ọ̀tá Mú Jesu 1 Lẹ́yìn tí Jesu ti gba adura yìí tán, òun ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí òdìkejì àfonífojì odò Kidironi. Ọgbà kan wà níbẹ̀. Ó…
1 Nígbà náà ni Pilatu mú Jesu, ó ní kí wọ́n nà án. 2 Àwọn ọmọ-ogun bá fi ìtàkùn ẹlẹ́gùn-ún hun adé, wọ́n fi dé e lórí; wọn wọ̀ ọ́…
Ajinde Jesu 1 Ní kutukutu ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, kí ilẹ̀ tó mọ́, Maria Magidaleni lọ sí ibojì náà, ó rí i pé wọ́n ti yí òkúta kúrò lẹ́nu rẹ̀. 2…
Jesu Fara Han Àwọn Ọmọ-Ẹ̀yìn Meje 1 Lẹ́yìn èyí, Jesu tún fara han àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ní òkun Tiberiasi. Bí ó ṣe farahàn wọ́n nìyí: 2 Simoni Peteru, ati Tomasi tí…
Jesu Ṣe Ìlérí Ẹ̀mí Mímọ́ 1 Tiofilu mi ọ̀wọ́n: Ninu ìwé mi àkọ́kọ́, mo ti sọ nípa gbogbo ohun tí Jesu ṣe ati ẹ̀kọ́ tí ó ń kọ́ àwọn eniyan,…
Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ti Ṣe Dé 1 Ní ọjọ́ Pẹntikọsti, gbogbo wọn wà pọ̀ ní ibìkan náà. 2 Lójijì ìró kan dún láti ọ̀run, ó dàbí ìgbà tí afẹ́fẹ́ líle…