ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3
A Wo Arọ Kan Sàn Lẹ́nu Ọ̀nà Tẹmpili 1 Ní agogo mẹta ọ̀sán, Peteru ati Johanu gòkè lọ sí Tẹmpili ní àkókò adura. 2 Ọkunrin kan wà tí wọn máa…
A Wo Arọ Kan Sàn Lẹ́nu Ọ̀nà Tẹmpili 1 Ní agogo mẹta ọ̀sán, Peteru ati Johanu gòkè lọ sí Tẹmpili ní àkókò adura. 2 Ọkunrin kan wà tí wọn máa…
A Mú Peteru ati Johanu Wá siwaju Ìgbìmọ̀ Àwọn Juu 1 Bí Peteru ti ń bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Johanu wà lọ́dọ̀ rẹ̀, àwọn alufaa ati olórí àwọn ẹ̀ṣọ́…
Ìtàn Anania ati Safira 1 Ọkunrin kan tí ń jẹ́ Anania pẹlu Safira, iyawo rẹ̀, ta ilẹ̀ kan. 2 Ọkunrin yìí yọ sílẹ̀ ninu owó tí wọ́n rí lórí rẹ̀,…
A Yan Àwọn Olùrànlọ́wọ́ Meje 1 Nígbà tí ó yá, tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu ń pọ̀ sí i, ìkùnsínú bẹ̀rẹ̀ láàrin àwọn tí ó ń sọ èdè Giriki ati àwọn…
Ọ̀rọ̀ Tí Stefanu Sọ 1 Olórí Alufaa bá bi í pé, “Ṣé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀ràn náà rí?” 2 Stefanu bá tẹnu bọ̀rọ̀, ó ní, “Ẹ̀yin arakunrin ati baba mi, ẹ…
1 Saulu bá wọn lọ́wọ́ sí ikú rẹ̀. Saulu Ṣe Inúnibíni Sí Ìjọ Kristi Láti ọjọ́ náà ni inúnibíni ńlá ti bẹ̀rẹ̀ sí ìjọ tí ó wà ní Jerusalẹmu. Gbogbo…
Saulu di Onigbagbọ 1 Ní gbogbo àkókò yìí, Saulu ń fi ikú dẹ́rùba àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Oluwa. Ó lọ sọ́dọ̀ Olórí Alufaa, 2 ó gba ìwé lọ́dọ̀ rẹ̀ láti lọ sí…
Ìtàn Peteru ati Kọniliu 1 Ọkunrin kan wà ní Kesaria tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kọniliu. Ó jẹ́ balogun ọ̀rún ti ẹgbẹ́ tí à ń pè ní Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun…
Peteru Ròyìn fún Ìjọ ní Jerusalẹmu 1 Àwọn aposteli ati àwọn onigbagbọ yòókù tí ó wà ní Judia gbọ́ pé àwọn tí kì í ṣe Juu náà ti gba ọ̀rọ̀…
Inúnibíni sí ìjọ 1 Ní àkókò náà Hẹrọdu ọba bẹ̀rẹ̀ sí ṣe inúnibíni sí àwọn kan ninu ìjọ. 2 Ó bẹ́ Jakọbu arakunrin Johanu lórí. 3 Nígbà tí ó rí…