ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 13

A Yan Banaba ati Saulu fún Iṣẹ́ Pataki 1 Àwọn wolii ati àwọn olùkọ́ wà ninu ìjọ tí ó wà ní Antioku. Ninu wọn ni Banaba ati Simeoni tí wọn…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 14

Iṣẹ́ Paulu ati Banaba ní Ikoniomu 1 Nígbà tí wọ́n dé Ikoniomu, wọ́n lọ sí ilé ìpàdé àwọn Juu gẹ́gẹ́ bí ìṣe wọn. Wọ́n sọ̀rọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọpọlọpọ ninu àwọn…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 15

Ìgbìmọ̀ Ìjọ Jerusalẹmu 1 Àwọn kan wá láti Judia tí wọn ń kọ́ àwọn onigbagbọ pé, “Bí ẹ kò bá kọlà gẹ́gẹ́ bí àṣà ati Òfin Mose, a kò lè…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 16

Timoti ba Paulu ati Sila lọ 1 Paulu dé Dabe ati Listira. Onigbagbọ kan tí ń jẹ́ Timoti wà níbẹ̀. Ìyá rẹ̀ jẹ́ Juu tí ó gba Jesu gbọ́; ṣugbọn…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17

Ìdàrúdàpọ̀ ní Tẹsalonika 1 Wọ́n kọjá ní Amfipoli ati Apolonia kí wọn tó dé Tẹsalonika. Ilé ìpàdé àwọn Juu kan wà níbẹ̀. 2 Gẹ́gẹ́ bí àṣà Paulu, ó wọ ibẹ̀…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18

Iṣẹ́ Paulu ní Kọrinti 1 Lẹ́yìn èyí, Paulu kúrò ní Atẹni, ó lọ sí Kọrinti. 2 Ó rí Juu kan níbẹ̀, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Akuila, ará Pọntu. Òun…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 19

Paulu Dé Efesu 1 Nígbà tí Apolo wà ní Kọrinti, Paulu gba ọ̀nà ilẹ̀ la àwọn ìlú tí ó wà ní àríwá Antioku kọjá títí ó fi dé Efesu. Ó…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20

Paulu lọ sí Masedonia ati Ilẹ̀ Giriki 1 Nígbà tí rògbòdìyàn náà kásẹ̀, Paulu ranṣẹ pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu. Ó gbà wọ́n níyànjú, ó sì dágbére fún wọn, ó bá…

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 21

Ìrìn Àjò Paulu sí Jerusalẹmu 1 Nígbà tí a dágbére fún wọn tán, ọkọ̀ ṣí. A wá lọ tààrà sí Kosi. Ní ọjọ́ keji a dé Rodọsi. Láti ibẹ̀ a…