ROMU 15

Ẹ Máa Ṣe Ohun Tí Ó Tẹ́ Ẹlòmíràn lọ́rùn 1 Ó yẹ kí àwa tí a jẹ́ alágbára ninu igbagbọ máa fara da àwọn nǹkan tí àwọn tí igbagbọ wọn…

ROMU 16

Paulu Kí Ọpọlọpọ Eniyan ninu Ìjọ Romu 1 Mo fẹ́ kí ẹ gba Febe bí arabinrin wa, ẹni tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọ tí ó wà ní Kẹnkiria. 2 Ẹ…

KỌRINTI KINNI 1

Ìkíni 1 Èmi Paulu, tí Ọlọrun pè láti jẹ́ òjíṣẹ́ Kristi Jesu, ati Sositene arakunrin wa ni à ń kọ ìwé yìí– 2 Sí ìjọ Ọlọrun ti ó wà ní…

KỌRINTI KINNI 2

Paulu Ń Waasu Kristi Tí Wọ́n Kàn Mọ́ Agbelebu 1 Ẹ̀yin ará, nígbà tí mo dé ọ̀dọ̀ yín, n kò wá fi ọ̀rọ̀ dídùn tabi ọgbọ́n eniyan kéde àṣírí Ọlọrun…

KỌRINTI KINNI 3

Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun 1 Ẹ̀yin ará, n kò lè ba yín sọ̀rọ̀ bí ẹni ti Ẹ̀mí, bíkòṣe bí ẹlẹ́ran-ara, àní gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ọwọ́ ninu Kristi. 2 Wàrà ni mo ti…

KỌRINTI KINNI 4

Iṣẹ́ Àwọn Aposteli 1 Bí ó ti yẹ kí eniyan máa rò nípa wa ni pé a jẹ́ iranṣẹ Kristi ati ìríjú àwọn nǹkan àṣírí Ọlọrun. 2 Ohun tí à…

KỌRINTI KINNI 5

Paulu Ṣe Ìdájọ́ lórí Ìwà Ìbàjẹ́ 1 A gbọ́ dájúdájú pé ìwà àgbèrè wà láàrin yín, irú èyí tí kò tilẹ̀ sí láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu. A…

KỌRINTI KINNI 6

Onigbagbọ Ń Pe Ara Wọn Lẹ́jọ́ Níwájú Àwọn Alaigbagbọ 1 Kí ló dé tí ẹni tí ó bá ní ẹ̀sùn sí ẹnìkejì rẹ̀ fi ń gbé ẹjọ́ lọ siwaju àwọn…

KỌRINTI KINNI 7

Èrò nípa Igbeyawo 1 Ọ̀rọ̀ lórí àwọn nǹkan tí ẹ kọ nípa rẹ̀, ó dára tí ọkunrin bá lè ṣe é kí ó má ní obinrin rara. 2 Ṣugbọn nítorí…

KỌRINTI KINNI 8

Oúnjẹ Tí A Fi Rúbọ fún Oriṣa 1 Ó wá kan ọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan tí a fi rúbọ fún oriṣa. A mọ̀ pé, “Gbogbo wa ni a ní ìmọ̀,”…