LEFITIKU 11

Àwọn Ẹranko Tí Ó Tọ̀nà láti Jẹ 1 OLUWA rán Mose ati Aaroni pé 2 kí wọ́n sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn ẹran tí wọ́n lè jẹ lára…

LEFITIKU 12

Ìwẹ̀nùmọ́ Àwọn Obinrin Lẹ́yìn Ìbímọ 1 OLUWA ní kí Mose 2 sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Bí obinrin kan bá lóyún tí ó sì bí ọmọkunrin, ó di aláìmọ́…

LEFITIKU 13

Àwọn Òfin tí ó Jẹmọ́ Àrùn Ara 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé, 2 “Nígbà tí ibìkan bá lé lára eniyan, tabi tí ara eniyan bá wú tí…

LEFITIKU 14

Ìwẹ̀nùmọ́ lẹ́yìn Àrùn Ara 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Òfin tí ó jẹmọ́ ti ọjọ́ ìwẹ̀nùmọ́ adẹ́tẹ̀ nìyí: kí wọ́n mú adẹ́tẹ̀ náà wá sí ọ̀dọ̀ alufaa. 3…

LEFITIKU 15

Àwọn Ohun Àìmọ́ tí Ń Jáde Lára 1 OLUWA ní kí Mose ati Aaroni 2 sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Nígbà tí nǹkan bá dà jáde lára ọkunrin, nǹkan…

LEFITIKU 16

Ọjọ́ Ètùtù 1 Lẹ́yìn tí meji ninu àwọn ọmọ Aaroni kú, nígbà tí wọ́n fi iná tí kò mọ́ rúbọ sí OLUWA, OLUWA bá sọ fún Mose pé, 2 “Sọ…

LEFITIKU 17

Ẹ̀jẹ̀ Lọ́wọ̀–Ninu Rẹ̀ Ni Ẹ̀mí wà 1 OLUWA sọ fún Mose pé 2 kí ó sọ fún Aaroni, ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli pé, “Ohun tí…

LEFITIKU 18

Àwọn Èèwọ̀ tí Ó Jẹmọ́ Bíbá Obinrin Lòpọ̀ 1 OLUWA ní kí Mose, 2 sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín. 3 Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe…

LEFITIKU 19

Àwọn Òfin Tí Wọ́n Jẹmọ́ Ẹ̀tọ́ ati Jíjẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose 2 pé kí ó sọ fún ìjọ eniyan Israẹli pé “Ẹ jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́…

LEFITIKU 20

Ìjìyà fún Ìwà Àìgbọràn 1 OLUWA sọ fún Mose 2 pé kí ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wọn ati àwọn àlejò, tí wọn ń ṣe àtìpó…