LEFITIKU 21

Àwọn Alufaa Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Aaroni pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wọn kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di…

LEFITIKU 22

Àwọn Ohun Ìrúbọ Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA rán Mose pé, 2 “Sọ fún Aaroni ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀ pé, kí wọ́n máa fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ lo àwọn nǹkan mímọ́ tí…

LEFITIKU 23

Àwọn Àjọ̀dún Ẹ̀sìn 1 OLUWA sọ fún Mose 2 pé kí ó sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn àjọ̀dún tí èmi OLUWA yàn tí ó gbọdọ̀ kéde gẹ́gẹ́ bí…

LEFITIKU 24

Ìtọ́jú Àwọn Fìtílà 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn eniyan Israẹli pé kí wọn mú ojúlówó òróró olifi wá fún àtùpà ilé mímọ́ mi, kí ó…

LEFITIKU 25

Ọdún Keje 1 OLUWA bá Mose sọ̀rọ̀ lórí òkè Sinai, ó ní, 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí n óo fun yín,…

LEFITIKU 26

Ibukun fún Ìgbọràn 1 “Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe oriṣa-koriṣa kan fún ara yín, tabi kí ẹ gbé ère gbígbẹ́ kalẹ̀, tabi kí ẹ ri ọ̀wọ̀n òkúta gbígbẹ́ mọ́lẹ̀, kí ẹ…

LEFITIKU 27

Àwọn Òfin tí Ó Jẹmọ́ Ohun tí a fi fún OLUWA 1 OLUWA sọ fun Mose 2 pé kí ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Bí ẹnìkan bá jẹ́jẹ̀ẹ́…

NỌMBA 1

Ètò Ìkànìyàn Àkọ́kọ́ láàrin Àwọn Ọmọ Israẹli 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù keji, ní ọdún keji tí àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, OLUWA sọ fún Mose ninu…

NỌMBA 2

Ètò Pípa Àgọ́ Ní Ẹlẹ́yà-mẹ̀yà 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé: 2 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli yóo bá pàgọ́ wọn, kí olukuluku máa pàgọ́ rẹ̀ lábẹ́ àsíá…

NỌMBA 3

Àwọn Ọmọ Aaroni 1 Àwọn wọnyi ni ìdílé Aaroni ati ti Mose, nígbà tí OLUWA bá Mose sọ̀rọ̀ ní orí òkè Sinai. 2 Orúkọ àwọn ọmọ Aaroni lọkunrin nìwọ̀nyí: Nadabu…