NỌMBA 4
Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi–Ìdílé Kohati 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé: 2 “Ẹ ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrin àwọn ọmọ Lefi, ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba…
Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi–Ìdílé Kohati 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé: 2 “Ẹ ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrin àwọn ọmọ Lefi, ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba…
Àwọn Aláìmọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n lé gbogbo àwọn adẹ́tẹ̀ kúrò ní ibùdó wọn, gbogbo àwọn tí ó ni ọyún…
Òfin fún Àwọn Nasiri 1 OLUWA sọ fún Mose kí ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, 2 “Nígbà tí ọkunrin tabi obinrin kan bá ṣe ìlérí láti di Nasiri,…
Ẹbọ Àwọn Olórí 1 Ní ọjọ́ tí Mose gbé Àgọ́ Àjọ dúró, tí ó sì ta òróró sí i tòun ti gbogbo nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀, ati pẹpẹ…
Ìgbékalẹ̀ Fìtílà 1 OLUWA rán Mose pé 2 kí ó sọ fún Aaroni pé, nígbà tí Aaroni bá tan fìtílà mejeeje, kí ó gbé wọn sórí ọ̀pá fìtílà kí wọ́n…
Àjọ Ìrékọjá Keji 1 Ní oṣù kinni, ọdún keji tí àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní Ijipti, OLUWA sọ fún Mose ninu aṣálẹ̀ Sinai pé, 2 “Kí àwọn ọmọ Israẹli…
Àwọn Fèrè Fadaka 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Fi fadaka tí wọ́n fi òòlù lù ṣe fèrè meji fún pípe àwọn ọmọ Israẹli jọ ati títú ibùdó palẹ̀….
Ibi tí Wọn sọ ní Tabera 1 Nígbà tí ó yá àwọn eniyan náà bẹ̀rẹ̀ sí kùn sí OLUWA nípa ìṣòro wọn. Nígbà tí OLUWA gbọ́ kíkùn wọn, inú bí…
Ìjìyà Miriamu 1 Miriamu ati Aaroni sọ̀rọ̀ òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ ọmọbinrin ará Kuṣi ní iyawo. 2 Wọn ń wí pé, “Ṣé Mose nìkan ni OLUWA ti…
Mose Rán Amí lọ sí Ilẹ̀ Kenaani 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Rán amí lọ wo ilẹ̀ Kenaani tí mo fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹnìkọ̀ọ̀kan tí ó bá…