NỌMBA 14
Àwọn Eniyan náà Kùn 1 Gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí ké, wọn sì fi gbogbo òru ọjọ́ náà sọkún. 2 Gbogbo wọn ń kùn sí Mose ati Aaroni pé, “Ó…
Àwọn Eniyan náà Kùn 1 Gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí ké, wọn sì fi gbogbo òru ọjọ́ náà sọkún. 2 Gbogbo wọn ń kùn sí Mose ati Aaroni pé, “Ó…
Àwọn Òfin nípa Ìrúbọ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, 2 bí ẹ bá dé ilẹ̀ tí mo fún yín láti máa gbé, 3…
Ọ̀tẹ̀ tí Kora, Datani ati Abiramu Dì 1 Kora ọmọ Iṣari láti inú ìdílé Kohati ọmọ Lefi, pẹlu Datani ati Abiramu àwọn ọmọ Eliabu, pẹlu Ooni ọmọ Peleti láti inú…
Ọ̀pá Aaroni 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Gba ọ̀pá mejila láti ọwọ́ àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀pá kọ̀ọ̀kan láti ọwọ́ olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, kí o sì kọ orúkọ olukuluku…
Iṣẹ́ Àwọn Alufaa ati Àwọn Ọmọ Lefi 1 OLUWA sọ fún Aaroni pé, “Ìwọ, ati àwọn ọmọ rẹ, ati ìdílé baba rẹ ni yóo jìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n bá dá…
Eérú Mààlúù Pupa náà 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé, 2 “Ìlànà tí èmi OLUWA fi lélẹ̀ nìyí: Ẹ sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n mú ẹgbọ̀rọ̀…
Ohun Tí Ó Ṣẹlẹ̀ ní Kadeṣi 1 Ní oṣù kinni, àwọn ọmọ Israẹli dé aṣálẹ̀ Sini, wọ́n sì ṣe ibùdó wọn sí Kadeṣi. Níbẹ̀ ni Miriamu kú sí, tí wọn…
Ìṣẹ́gun lórí Àwọn Ará Kenaani 1 Nígbà tí ọba Aradi ará Kenaani tí ń gbé ìhà gúsù ní Nẹgẹbu Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń gba ọ̀nà Atarimu bọ̀,…
Ọba Moabu Ranṣẹ Pe Balaamu 1 Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò, wọ́n lọ pa àgọ́ wọn sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní òdìkejì Jọdani tí ó kọjú sí Jẹriko. 2 Nígbà tí…
Àsọtẹ́lẹ̀ Àkọ́kọ́ tí Balaamu Sọ 1 Balaamu sọ fún Balaki pé, “Tẹ́ pẹpẹ meje sí ibí yìí fún mi kí o sì pèsè akọ mààlúù meje ati àgbò meje.” 2…