NỌMBA 24

1 Nígbà tí Balaamu rí i pé OLUWA ń súre fún àwọn ọmọ Israẹli, kò lọ bíi ti iṣaaju láti bá OLUWA pàdé. Ṣugbọn ó kọjú sí aṣálẹ̀, 2 ó…

NỌMBA 25

Àwọn Ọmọ Israẹli ní Peori 1 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí àfonífojì Ṣitimu, àwọn ọkunrin wọn ń bá àwọn ọmọbinrin Moabu tí wọ́n wà níbẹ̀ ṣe àgbèrè. 2…

NỌMBA 26

Ètò Ìkànìyàn Keji 1 Lẹ́yìn àjàkálẹ̀ àrùn náà, OLUWA sọ fún Mose ati Eleasari alufaa ọmọ Aaroni pé, 2 “Ẹ ka iye àwọn ọmọ Israẹli, àwọn tí wọ́n tó ẹni…

NỌMBA 27

Àwọn Ọmọbinrin Selofehadi 1 Nígbà náà ni Mahila, Noa, Hogila, Milika ati Tirisa, àwọn ọmọbinrin Selofehadi, ọmọ Heferi, ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri, ọmọ Manase, ti ìdílé Manase, ọmọ Josẹfu, 2…

NỌMBA 28

Ẹbọ Àtìgbàdégbà 1 OLUWA sọ fún Mose 2 pé kí ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọn máa mú ọrẹ wá fún ohun ìrúbọ sí òun OLUWA ní àkókò…

NỌMBA 29

Ẹbọ Àjọ̀dún Ọdún Titun 1 “Ní ọjọ́ kinni oṣù keje, ẹ óo máa ní àpèjọ mímọ́, ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ líle kankan. Ó jẹ́ ọjọ́ tí ẹ óo…

NỌMBA 30

Ìlànà nípa Ẹ̀jẹ́ Jíjẹ́ 1 Mose sọ fún àwọn olórí àwọn ẹ̀yà Israẹli àwọn ohun tí OLUWA pa láṣẹ: 2 Bí ọmọkunrin kan bá bá OLUWA jẹ́jẹ̀ẹ́ tabi tí ó…

NỌMBA 31

Wọ́n Dojú Ogun Mímọ́ kọ Midiani 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Fìyà jẹ àwọn ará Midiani fún ohun tí wọ́n ṣe sí àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn náà, o…

NỌMBA 32

Àwọn Ẹ̀yà Ìlà Oòrùn Jọdani 1 Nígbà tí àwọn ọmọ Reubẹni ati àwọn ọmọ Gadi, tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn pupọ, rí ilẹ̀ Jaseri ati ilẹ̀ Gileadi pé ibẹ̀ dára…

NỌMBA 33

Ìrìn Àjò láti Ijipti sí Moabu 1 Ibi tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí ninu ìrìn àjò wọn láti ìgbà tí wọn ti kúrò ní Ijipti lábẹ́ àṣẹ Mose ati…