ÀWỌN ADÁJỌ́ 20

Israẹli Múra Ogun 1 Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jáde wá, bẹ̀rẹ̀ láti Dani ní apá ìhà àríwá títí dé Beeriṣeba ní apá ìhà gúsù ilẹ̀ Israẹli ati àwọn tí wọ́n…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 21

Àwọn Ẹ̀yà Bẹnjamini Fẹ́ Iyawo 1 Àwọn ọmọ Israẹli ti búra nígbà tí wọ́n wà ní Misipa pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wa kò ní fi ọmọ rẹ̀ fún ará Bẹnjamini.” 2…

RUTU 1

Elimeleki ati Ìdílé Rẹ̀ Lọ láti Máa Gbé ní Ilẹ̀ Moabu 1 Ní àkókò tí àwọn adájọ́ ń ṣe olórí ní ilẹ̀ Israẹli, ìyàn ńlá kan mú ní ilẹ̀ náà….

RUTU 2

Rutu Ṣiṣẹ́ ninu Oko Boasi 1 Ní àkókò yìí, ọkunrin ọlọ́rọ̀ kan wà ninu ìdílé Elimeleki, ẹbí kan náà ni ọkunrin yìí ati ọkọ Naomi. Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Boasi….

RUTU 3

Rutu rí Ọkọ Fẹ́ 1 Lẹ́yìn náà, Naomi pe Rutu, ó ní, “Ọmọ mi, ó tó àkókò láti wá ọkọ fún ọ, kí ó lè dára fún ọ. 2 Ṣé…

RUTU 4

Boasi Ṣú Rutu Lópó 1 Boasi bá lọ sí ẹnu ibodè ìlú, ó jókòó níbẹ̀. Bí ìbátan ọkọ Rutu tí ó súnmọ́ ọn, tí Boasi sọ nípa rẹ̀ ti ń…

SAMUẸLI KINNI 1

Elikana ati Ìdílé Rẹ̀ ní Ìlú Ṣilo 1 Ọkunrin kan wà ninu ẹ̀yà Efuraimu tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elikana, ará Ramataimu-sofimu, ní agbègbè olókè Efuraimu. Orúkọ baba rẹ̀ ni…

SAMUẸLI KINNI 2

Adura Hana 1 Hana bá gbadura báyìí pé: “Ọkàn mi kún fún ayọ̀ ninu OLUWA, Ó sọ mí di alágbára; mò ń fi àwọn ọ̀tá mi rẹ́rìn-ín, nítorí mò ń…

SAMUẸLI KINNI 3

OLUWA Fara Han Samuẹli 1 Ní gbogbo àkókò tí Samuẹli wà ní ọmọde, tí ó ń ṣiṣẹ́ fún OLUWA lábẹ́ Eli, OLUWA kò fi bẹ́ẹ̀ bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀ mọ́,…

SAMUẸLI KINNI 4

Wọ́n Gba Àpótí Ẹ̀rí Lọ́wọ́ Àwọn Ọmọ Israẹli 1 Ní àkókò náà, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli, àwọn ọmọ Israẹli náà bá…