SAMUẸLI KINNI 5

Àpótí Ẹ̀rí Bọ́ Sọ́wọ́ Àwọn Ará Filistia 1 Lẹ́yìn tí àwọn ará Filistia gba àpótí Ọlọrun lọ́wọ́ àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n gbé e láti Ebeneseri lọ sí Aṣidodu. 2 Wọ́n…

SAMUẸLI KINNI 6

Wọ́n Dá Àpótí Ẹ̀rí Pada 1 Lẹ́yìn tí àpótí OLUWA ti wà ní ilẹ̀ Filistini fún oṣù meje, 2 àwọn ará ilẹ̀ náà pe àwọn babalóòṣà wọn ati àwọn adáhunṣe…

SAMUẸLI KINNI 7

1 Àwọn ará ìlú Kiriati Jearimu wá, wọ́n gbé àpótí OLUWA náà lọ sí ilé Abinadabu, tí ń gbé orí òkè kan. Wọ́n ya Eleasari, ọmọ rẹ̀ sí mímọ́, láti…

SAMUẸLI KINNI 8

Àwọn Ọmọ Israẹli Bèèrè fún Ọba 1 Nígbà tí àgbà dé sí Samuẹli, ó fi àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe adájọ́ ní ilẹ̀ Israẹli. 2 Joẹli ni orúkọ àkọ́bí, èyí àbúrò…

SAMUẸLI KINNI 9

Saulu Pàdé Samuẹli 1 Ọkunrin ọlọ́rọ̀ kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kiṣi, ọmọ Abieli, ọmọ Serori, ọmọ Bekorati, ọmọ Afaya láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini. 2 Ó ní ọmọkunrin kan…

SAMUẸLI KINNI 10

1 Nígbà náà ni Samuẹli mú ìgò òróró olifi kan, ó tú u lé Saulu lórí. Ó fi ẹnu kò ó lẹ́nu, ó sì wí fún un pé, “OLUWA fi…

SAMUẸLI KINNI 11

Saulu Ṣẹgun Àwọn Ará Amoni 1 Nahaṣi, ọba Amoni, kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀, wọ́n lọ gbógun ti ìlú Jabeṣi Gileadi. Àwọn ará Jabeṣi bá sọ fún Nahaṣi pé, “Jẹ́…

SAMUẸLI KINNI 12

Ọ̀rọ̀ ìdágbére Samuẹli 1 Lẹ́yìn náà, Samuẹli wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Mo ti ṣe ohun tí ẹ ní kí n ṣe. Mo ti fi ẹnìkan jọba lórí yín….

SAMUẸLI KINNI 13

Àwọn Ọmọ Israẹli Gbógun ti Àwọn Ará Filistia 1 Saulu jẹ́ bíi ọmọ ọgbọ̀n ọdún… nígbà tí ó jọba lórí Israẹli. Ó sì wà lórí oyè fún bíi ogoji ọdún….

SAMUẸLI KINNI 14

Jonatani Hùwà Akikanju 1 Ní ọjọ́ kan, Jonatani, ọmọ Saulu, wí fún ọdọmọkunrin tí ó ń ru ihamọra rẹ̀ pé, “Jẹ́ kí á lọ sí òdìkejì ibùdó àwọn ọmọ ogun…