SAMUẸLI KEJI 4
Wọ́n Pa Iṣiboṣẹti 1 Nígbà tí Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu gbọ́ pé wọ́n ti pa Abineri ní Heburoni, ẹ̀rù bà á gidigidi, ìdààmú sì bá gbogbo àwọn ọmọ Israẹli. 2 Iṣiboṣẹti…
Wọ́n Pa Iṣiboṣẹti 1 Nígbà tí Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu gbọ́ pé wọ́n ti pa Abineri ní Heburoni, ẹ̀rù bà á gidigidi, ìdààmú sì bá gbogbo àwọn ọmọ Israẹli. 2 Iṣiboṣẹti…
Dafidi Di Ọba Israẹli ati ti Juda 1 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn ẹ̀yà Israẹli tọ Dafidi lọ ní Heburoni, wọ́n sọ fún un pé, “Ara kan náà ni wá, ẹ̀jẹ̀…
Wọ́n Gbé Àpótí Ẹ̀rí Wá sí Jerusalẹmu 1 Dafidi tún pe gbogbo àwọn akikanju ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli jọ; wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbaarun (30,000). 2 Ó kó…
Iṣẹ́ Tí Natani Jẹ́ fún Dafidi 1 Lẹ́yìn tí Dafidi ọba ti bẹ̀rẹ̀ sí gbé inú ààfin rẹ̀, tí OLUWA ti fi ọkàn rẹ̀ balẹ̀, tí ó sì dáàbò bò…
Àwọn Ogun Tí Dafidi Jà ní Àjàṣẹ́gun 1 Lẹ́yìn náà, Dafidi ọba gbógun ti àwọn ará Filistia, ó ṣẹgun wọn, ó sì gba ìlú Mẹtẹgi-ama lọ́wọ́ wọn. 2 Ó ṣẹgun…
Dafidi ati Mẹfiboṣẹti 1 Ní ọjọ́ kan, Dafidi bèèrè pé, “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni kù ninu gbogbo ìdílé Saulu tí mo lè ṣoore fún nítorí Jonatani?” 2 Ọkunrin kan wà tí orúkọ…
Dafidi Ṣẹgun Àwọn Ará Amoni ati Àwọn Ará Siria 1 Lẹ́yìn èyí, ni Nahaṣi, ọba Amoni kú, Hanuni, ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè. 2 Dafidi ọba wí pé, “N óo…
Dafidi ati Batiṣeba 1 Ní àkókò ìgbà tí igi ń rúwé, tí ó jẹ́ àkókò tí gbogbo àwọn ọba máa ń lọ sójú ogun, Dafidi rán Joabu ati àwọn ọ̀gágun…
Iṣẹ́ tí Natani Jẹ́ ati Ìrònúpìwàdà Dafidi 1 OLUWA rán Natani wolii sí Dafidi. Natani bá tọ Dafidi lọ, ó sì sọ fún un pé, “Àwọn ọkunrin meji wà ninu…
Amnoni ati Tamari 1 Absalomu ọmọ Dafidi ní arabinrin kan tí ó jẹ́ arẹwà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tamari. Dafidi tún ní ọmọkunrin mìíràn tí ń jẹ́ Amnoni. Amnoni yìí…