SAMUẸLI KEJI 14

Joabu Ṣe Ètò Àtipadà Absalomu 1 Joabu, ọmọ Seruaya, ṣe akiyesi pé ọkàn Absalomu ń fa Dafidi pupọ. 2 Nítorí náà, ó ranṣẹ sí ọlọ́gbọ́n obinrin kan, tí ń gbé…

SAMUẸLI KEJI 15

Absalomu Dìtẹ̀ mọ́ Dafidi 1 Lẹ́yìn èyí, Absalomu wá kẹ̀kẹ́ ogun kan, ati àwọn ẹṣin, ati aadọta ọkunrin tí wọn yóo máa sáré níwájú rẹ̀. 2 A máa jí ní…

SAMUẸLI KEJI 16

Dafidi ati Siba 1 Ní gẹ́rẹ́ tí Dafidi kọjá góńgó orí òkè náà, Siba, iranṣẹ Mẹfiboṣẹti pàdé rẹ̀, ó ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bíi mélòó kan bọ̀ tí ó di…

SAMUẸLI KEJI 17

Huṣai Ṣi Absalomu lọ́nà 1 Lẹ́yìn náà, Ahitofeli wí fún Absalomu pé, “Jẹ́ kí n ṣa ẹgbaafa (12,000) ninu àwọn ọmọ ogun, kí n sì bẹ̀rẹ̀ sí lépa Dafidi lọ…

SAMUẸLI KEJI 18

Wọ́n Ṣẹgun Absalomu, Wọ́n sì Pa Á 1 Dafidi kó gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó pín wọn ní ọgọọgọrun-un (100) ati ẹgbẹẹgbẹrun (1,000), ó fi balogun kọ̀ọ̀kan ṣe olórí…

SAMUẸLI KEJI 19

Joabu Bínú sí Dafidi 1 Àwọn kan lọ sọ fún Joabu pé, ọba ń sọkún, ó sì ń ṣọ̀fọ̀ Absalomu. 2 Nítorí náà, ìṣẹ́gun ọjọ́ náà pada di ìbànújẹ́ fún…

SAMUẸLI KEJI 20

Ọ̀tẹ̀ Ṣeba 1 Aláìníláárí ẹ̀dá kan wà ní ààrin àwọn ará Giligali tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ṣeba, ọmọ Bikiri, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini. Ọkunrin yìí fọn fèrè, ó ní,…

SAMUẸLI KEJI 21

Wọ́n Pa Àwọn Ọmọ Ọmọ Saulu 1 Ní àkókò ìjọba Dafidi, ìyàn ńlá kan mú, fún odidi ọdún mẹta. Dafidi bá lọ wádìí ọ̀rọ̀ náà lọ́dọ̀ OLUWA. OLUWA sì dáhùn…

SAMUẸLI KEJI 22

Orin Ìṣẹ́gun Tí Dafidi Kọ 1 Nígbà tí OLUWA gba Dafidi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ati lọ́wọ́ Saulu, Dafidi kọ orin yìí sí OLUWA pé: 2 “OLUWA ni àpáta…

SAMUẸLI KEJI 23

Ọ̀rọ̀ Ìkẹyìn Dafidi 1 Ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dafidi nìyí; àní, ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ Dafidi, ọmọ Jese, tí a gbé ga ní Israẹli, ẹni àmì òróró Ọlọrun Jakọbu, olórin dídùn ní Israẹli: 2…