ÀWỌN ỌBA KINNI 10
Ìbẹ̀wò Ọbabinrin Ìlú Ṣeba 1 Nígbà tí ọbabinrin Ṣeba gbọ́ òkìkí ọgbọ́n Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti fi àwọn ìbéèrè tí ó takókó dán an wò. 2 Ó kó…
Ìbẹ̀wò Ọbabinrin Ìlú Ṣeba 1 Nígbà tí ọbabinrin Ṣeba gbọ́ òkìkí ọgbọ́n Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti fi àwọn ìbéèrè tí ó takókó dán an wò. 2 Ó kó…
Solomoni Yipada Kúrò lọ́dọ̀ Ọlọrun 1 Ọpọlọpọ àwọn obinrin àjèjì ni Solomoni fẹ́, lẹ́yìn ọmọ Farao, ọba Ijipti, tí ó kọ́kọ́ fẹ́, ó tún fẹ́ ará Moabu ati ará Amoni,…
Àwọn Ẹ̀yà Apá Ìhà Àríwá Dìtẹ̀, Wọ́n Sì Ya 1 Rehoboamu lọ sí Ṣekemu, nítorí pé gbogbo Israẹli ti péjọ níbẹ̀ láti fi jọba. 2 Nígbà tí Jeroboamu ọmọ Nebati…
1 OLUWA pàṣẹ fún wolii kan, ará Juda, pé kí ó lọ sí Bẹtẹli; nígbà tí ó débẹ̀ ó bá Jeroboamu tí ó dúró níwájú pẹpẹ láti sun turari. 2…
Ikú Ọmọ Jeroboamu Ọkunrin 1 Ní àkókò yìí Abija, ọmọ Jeroboamu ọba ṣàìsàn, 2 Jeroboamu wí fún aya rẹ̀ pé, “Dìde, kí o yíra pada, kí ẹnikẹ́ni má lè dá…
Abijamu, Ọba Juda 1 Ní ọdún kejidinlogun tí Jeroboamu jọba Israẹli, ni Abijamu gorí oyè ní ilẹ̀ Juda. 2 Ọdún mẹta ló fi jọba ní Jerusalẹmu. Maaka ọmọ Absalomu ni…
1 Ọlọrun rán wolii Jehu, ọmọ Hanani, pé kí ó sọ fún Baaṣa ọba pé, 2 “O kò jámọ́ nǹkankan tẹ́lẹ̀, kí n tó fi ọ́ ṣe olórí àwọn ọmọ…
Elija ati Ọ̀dá 1 Wolii kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elija, ará Tiṣibe, ní Gileadi, sọ fún Ahabu pé, “Bí OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí mò ń sìn ti wà…
Elija ati Àwọn Wolii Baali 1 Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, ní ọdún kẹta tí ọ̀dá ti dá, OLUWA sọ fún Elija pé, “Lọ fi ara rẹ han Ahabu ọba, n óo…
Elija, lórí Òkè Sinai 1 Ahabu ọba sọ gbogbo ohun tí Elija ṣe fún Jesebẹli, aya rẹ̀, ati bí ó ti pa gbogbo wolii oriṣa Baali. 2 Jesebẹli bá rán…