ÀWỌN ỌBA KEJI 18

Hesekaya, Ọba Juda 1 Ní ọdún kẹta tí Hoṣea, ọmọ Ela, jọba ní Israẹli ni Hesekaya, ọmọ Ahasi jọba ní Juda. 2 Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba,…

ÀWỌN ỌBA KEJI 19

Ọba Bèèrè Ìmọ̀ràn Lọ́wọ́ Aisaya 1 Nígbà tí Hesekaya ọba gbọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó fi aṣọ ọ̀fọ̀ bora, ó bá lọ sinu ilé OLUWA. 2 Ó rán…

ÀWỌN ỌBA KEJI 20

Àìsàn Hesekaya Ọba, ati Ìwòsàn Rẹ̀ 1 Ní àkókò kan Hesekaya ṣàìsàn tóbẹ́ẹ̀ tí ó fẹ́rẹ̀ kú. Wolii Aisaya ọmọ Amosi, wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún un pé, “OLUWA…

ÀWỌN ỌBA KEJI 21

Manase, Ọba Juda 1 Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hefisiba. 2 Manase…

ÀWỌN ỌBA KEJI 22

Josaya, Ọba Juda 1 Ọmọ ọdún mẹjọ ni Josaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanlelọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jedida ọmọ Adaya…

ÀWỌN ỌBA KEJI 23

Josaya pa Ìbọ̀rìṣà Run 1 Josaya bá pe ìpàdé gbogbo àwọn olórí Juda ati Jerusalẹmu. 2 Gbogbo wọn lọ sí ilé OLUWA pẹlu àwọn alufaa ati àwọn wolii ati gbogbo…

ÀWỌN ỌBA KEJI 24

1 Ní àkókò ìjọba Jehoiakimu ni Nebukadinesari, ọba Babiloni gbógun ti Jerusalẹmu, Jehoiakimu sì di iranṣẹ rẹ̀ fún ọdún mẹta. Lẹ́yìn náà, ó pada lẹ́yìn Nebukadinesari, ó sì ṣọ̀tẹ̀ sí…

ÀWỌN ỌBA KEJI 25

Ìṣubú Jerusalẹmu 1 Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kẹwaa ọdún kẹsan-an ìjọba rẹ̀, Nebukadinesari, ọba Babiloni, òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n dó tì í, wọ́n sì…

KRONIKA KINNI 1

Ìran Adamu títí Dé Orí Abrahamu 1 Adamu bí Seti, Seti bí Enọṣi. 2 Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi; 3 Jaredi bí Enọku, Enọku bí Metusela,…

KRONIKA KINNI 2

Àwọn Arọmọdọmọ Juda 1 Àwọn ọmọ Israẹli nìwọ̀nyí: Reubẹni, Simeoni, ati Lefi; Juda, Isakari, ati Sebuluni; 2 Dani, Josẹfu, ati Bẹnjamini; Nafutali, Gadi ati Aṣeri. 3 Juda bí ọmọ marun-un….