KRONIKA KINNI 3

Àwọn Ọmọ Dafidi Ọba 1 Àwọn ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Heburoni nìwọ̀nyí, bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn: Aminoni tí Ahinoamu ará Jesireeli bí fún un…

KRONIKA KINNI 4

Ìran Juda 1 Àwọn ọmọ Juda ni: Peresi, Hesironi, Kami, Huri, ati Ṣobali. 2 Ṣobali ni ó bí Reaaya. Reaaya sì bí Jahati. Jahati ni baba Ahumai ati Lahadi. Àwọn…

KRONIKA KINNI 5

Ìran Reubẹni 1 Reubẹni ni àkọ́bí Jakọbu, (Ṣugbọn nítorí pé Reubẹni fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn obinrin baba rẹ̀, baba rẹ̀ gba ipò àgbà lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì gbé e fún…

KRONIKA KINNI 6

Ìran Àwọn Olórí Alufaa 1 Àwọn ọmọ Lefi nìwọ̀nyí: Geṣomu, Kohati ati Merari. 2 Kohati bí ọmọkunrin mẹrin: Amramu, Iṣari, Heburoni ati Usieli. 3 Amramu bí ọmọ mẹta: Aaroni, Mose,…

KRONIKA KINNI 7

Àwọn Ìran Isakari 1 Àwọn mẹrin ni ọmọ Isakari: Tola, Pua, Jaṣubu ati Ṣimironi. 2 Àwọn ọmọ Tola ni: Usi, Refaaya, Jerieli, Jahimai, Ibisamu ati Ṣemueli, àwọn ni baálé ninu…

KRONIKA KINNI 8

Àwọn Ìran Bẹnjamini 1 Bẹnjamini bí ọmọkunrin marun-un, Bela ni àkọ́bí, lẹ́yìn rẹ̀ ni Aṣibeli, 2 lẹ́yìn rẹ̀, Ahara, lẹ́yìn rẹ̀, Nohahi, àbíkẹ́yìn rẹ̀ ni, Rafa. 3 Àwọn ọmọ Bela…

KRONIKA KINNI 9

Àwọn tí Wọ́n Dé láti Oko Ẹrú Babiloni 1 A kọ orúkọ àwọn ọmọ Israẹli sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìran wọn; a kọ wọ́n sinu ìwé Àwọn Ọba Israẹli. A kó…

KRONIKA KINNI 10

Ikú Saulu Ọba 1 Ogun bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Filistia ati àwọn ọmọ Israẹli. Àwọn ọmọ Israẹli sá fún àwọn ará Filistia, wọ́n sì pa ọpọlọpọ àwọn ọmọ Israẹli…

KRONIKA KINNI 11

Dafidi Jọba lórí Israẹli ati Juda 1 Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá parapọ̀, wọ́n wá sọ́dọ̀ Dafidi ní Heburoni, wọ́n ní, “Wò ó, ẹ̀jẹ̀ kan náà ni gbogbo wa pẹlu…

KRONIKA KINNI 12

Àwọn tí Wọ́n Kọ́kọ́ Jẹ́ Ọmọlẹ́yìn Dafidi Ọba láti Inú Ẹ̀yà Bẹnjamini 1 Àwọn ọkunrin wọnyi ni wọ́n lọ bá Dafidi ní Sikilagi, nígbà tí ó ń farapamọ́ fún Saulu,…