KRONIKA KINNI 13
A Gbé Àpótí Majẹmu kúrò ní Kiriati Jearimu 1 Dafidi jíròrò pẹlu àwọn ọ̀gágun ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun ati àwọn ti ọgọọgọrun-un, ati gbogbo àwọn olórí. 2 Lẹ́yìn náà ó sọ…
A Gbé Àpótí Majẹmu kúrò ní Kiriati Jearimu 1 Dafidi jíròrò pẹlu àwọn ọ̀gágun ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun ati àwọn ti ọgọọgọrun-un, ati gbogbo àwọn olórí. 2 Lẹ́yìn náà ó sọ…
Akitiyan Dafidi ní Jerusalẹmu 1 Hiramu, ọba Tire kó àwọn òṣìṣẹ́ ranṣẹ sí Dafidi, pẹlu igi kedari ati àwọn ọ̀mọ̀lé ati àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà láti bá a kọ́ ilé rẹ̀. 2…
Ìmúra láti Gbé Àpótí Majẹmu Pada 1 Dafidi kọ́ ọpọlọpọ ilé fún ara rẹ̀ ní ìlú Dafidi. Ó tọ́jú ibìkan fún Àpótí Majẹmu Ọlọrun. Ó sì pa àgọ́ lé e…
1 Wọ́n gbé Àpótí Majẹmu Ọlọrun kalẹ̀ ninu àgọ́ tí Dafidi ti tọ́jú sílẹ̀ fún un, wọ́n sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia níwájú Ọlọrun. 2 Nígbà tí Dafidi…
Iṣẹ́ tí Natani Jẹ́ fún Dafidi 1 Ní ọjọ́ kan ní àkókò tí Dafidi ọba ń gbe ààfin rẹ̀, ó sọ fún Natani, wolii, pé, “Wò ó, èmi ń gbé…
Àwọn Ogun tí Dafidi Jà ní Àjàṣẹ́gun 1 Lẹ́yìn náà, Dafidi gbógun ti àwọn Filistini, ó ṣẹgun wọn, ó sì jagun gba ìlú Gati ati àwọn ìletò agbègbè rẹ̀ lọ́wọ́…
Dafidi Ṣẹgun Àwọn Ará Amoni ati Àwọn Ará Siria 1 Nígbà tí ó yá, Nahaṣi, ọba àwọn ará Amoni kú, Hanuni ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀. 2 Dafidi ní,…
Dafidi Ṣẹgun Raba 1 Nígbà tí àkókò òtútù kọjá, ní àkókò tí àwọn ọba máa ń lọ jagun, Joabu gbógun ti ilẹ̀ Amoni; wọ́n dó ti ìlú Raba. Ṣugbọn Dafidi…
Dafidi Ṣe Ètò Ìkànìyàn 1 Satani fẹ́ ta jamba fún àwọn ọmọ Israẹli, nítorí náà ó gbó Dafidi láyà láti kà wọ́n. 2 Dafidi sọ fún Joabu ati àwọn ọ̀gágun…
1 Nítorí náà Dafidi pàṣẹ pé, “Ibí yìí ni ilé OLUWA Ọlọrun, ati pẹpẹ ẹbọ sísun yóo wà fún Israẹli.” Ìpalẹ̀mọ́ fún Kíkọ́ Tẹmpili 2 Dafidi pàṣẹ pé kí gbogbo…