KRONIKA KINNI 23

1 Nígbà tí Dafidi dàgbà, tí ó di arúgbó, ó fi Solomoni, ọmọ rẹ̀ jọba lórí Israẹli. Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi 2 Dafidi pe gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli, àwọn alufaa…

KRONIKA KINNI 24

Iṣẹ́ Àwọn Alufaa 1 Bí a ṣe pín àwọn ọmọ Aaroni nìyí: Aaroni ní ọmọkunrin mẹrin: Nadabu, Abihu, Eleasari ati Itamari. 2 Nadabu ati Abihu kú ṣáájú baba wọn láì…

KRONIKA KINNI 25

Àwọn Akọrin Inú Tẹmpili 1 Dafidi ati àwọn olórí ogun ya àwọn kan sọ́tọ̀ ninu àwọn ọmọ Asafu, Hemani ati ti Jedutuni láti máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ nígbà tí wọ́n bá…

KRONIKA KINNI 26

Àwọn Aṣọ́nà Tẹmpili 1 Bí a ti ṣe pín iṣẹ́ fún àwọn aṣọ́nà nìwọ̀nyí: Meṣelemaya, ọmọ Kore, ní ìdílé Asafu, ninu ìran Kora. 2 Meṣelemaya bí ọmọ meje, orúkọ wọn…

KRONIKA KINNI 27

Àwọn Ológun ati Ètò Òṣèlú 1 Àwọn wọnyi ni àwọn olórí ìdílé ati olórí ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun ati olórí ọgọọgọrun-un ọmọ ogun, ati àwọn olórí tí wọ́n jẹ́ aṣojú ọba…

KRONIKA KINNI 28

Ìlànà tí Dafidi Fi Lélẹ̀ fún Kíkọ́ Tẹmpili 1 Dafidi ọba pe gbogbo àwọn olórí ní ilẹ̀ Israẹli jọ sí Jerusalẹmu, àwọn olórí láàrin àwọn ẹ̀yà Israẹli, àwọn olórí àwọn…

KRONIKA KINNI 29

Àwọn Ẹ̀bùn láti fi Kọ́ Tẹmpili 1 Dafidi ọba sọ fún àpéjọpọ̀ àwọn eniyan pé, “Solomoni ọmọ mi, ẹnìkan ṣoṣo tí Ọlọrun yàn, ó kéré, kò tíì ní ìrírí, iṣẹ́…

KRONIKA KEJI 1

Solomoni Ọba Gbadura fún Ọgbọ́n 1 Solomoni, ọmọ Dafidi, fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, OLUWA Ọlọrun wà pẹlu rẹ̀, ó sì sọ ọ́ di ẹni ńlá. 2 Solomoni bá gbogbo àwọn…

KRONIKA KEJI 2

Ìpalẹ̀mọ́ fún Kíkọ́ Tẹmpili 1 Solomoni ọba pinnu láti kọ́ tẹmpili níbi tí àwọn eniyan yóo ti máa sin OLUWA ati láti kọ́ ààfin fún ara rẹ̀. 2 Ó kó…

KRONIKA KEJI 3

1 Solomoni bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ tẹmpili OLUWA ní Jerusalẹmu, níbi ìpakà Onani, ará Jebusi, lórí òkè Moraya, níbi tí OLUWA ti fi ara han Dafidi, baba rẹ̀; Dafidi ti tọ́jú…