KRONIKA KEJI 4
Àwọn Ohun Èlò Inú Tẹmpili 1 Solomoni ọba ṣe pẹpẹ idẹ kan tí ó gùn ní ogún igbọnwọ (mita 9), ìbú rẹ̀ náà sì jẹ́ ogún igbọnwọ (mita 9). Ó…
Àwọn Ohun Èlò Inú Tẹmpili 1 Solomoni ọba ṣe pẹpẹ idẹ kan tí ó gùn ní ogún igbọnwọ (mita 9), ìbú rẹ̀ náà sì jẹ́ ogún igbọnwọ (mita 9). Ó…
1 Nígbà tí Solomoni ọba parí gbogbo iṣẹ́ ilé OLUWA, ó kó gbogbo nǹkan tí Dafidi baba rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wá sinu ilé Ọlọrun: àwọn nǹkan bíi fadaka,…
Ọ̀rọ̀ tí Solomoni Bá Àwọn Eniyan Sọ 1 Solomoni ọba ní, “OLUWA, o ti sọ pé o óo máa gbé inú òkùnkùn biribiri. 2 Ṣugbọn nisinsinyii, mo ti kọ́ ilé…
Yíya Tẹmpili sí Mímọ́ 1 Nígbà tí Solomoni parí adura rẹ̀, iná kan ṣẹ́ láti ọ̀run, ó jó gbogbo ẹbọ sísun ati ọrẹ, ògo OLUWA sì kún inú tẹmpili. 2…
Àwọn Àsẹyọrí Solomoni 1 Ó gba Solomoni ní ogún ọdún láti kọ́ tẹmpili OLUWA ati ààfin tirẹ̀. 2 Lẹ́yìn náà, ó tún àwọn ìlú tí Huramu ọba, fún un kọ́,…
Ìbẹ̀wò Ọbabinrin Ṣeba sí Solomoni 1 Nígbà tí ọbabinrin ìlú Ṣeba gbọ́ nípa òkìkí Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti wá dán an wò pẹlu àwọn ìbéèrè tó le. Ó…
Àwọn Ẹ̀yà Ìhà Àríwá Dìtẹ̀ 1 Rehoboamu lọ sí Ṣekemu, nítorí pé gbogbo Israẹli ti péjọ sibẹ láti fi jọba. 2 Nígbà tí Jeroboamu, ọmọ Nebati, gbọ́, ó pada wá…
Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣemaaya 1 Nígbà tí Rehoboamu dé Jerusalẹmu, ó kó ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) àwọn akọni ọmọ ogun jọ láti inú ẹ̀yà Juda ati Bẹnjamini, láti bá àwọn ọmọ Israẹli jagun,…
Àwọn Ará Ijipti Gbógun ti Juda 1 Láìpẹ́, lẹ́yìn tí Rehoboamu fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ tí ó di alágbára, òun ati àwọn eniyan rẹ̀ kọ òfin OLUWA sílẹ̀. 2…
Ogun láàrin Abija ati Jeroboamu 1 Ní ọdún kejidinlogun ìjọba Jeroboamu ni Abija jọba ní ilẹ̀ Juda. 2 Ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹta. Orúkọ ìyá…