JẸNẸSISI 31

Jakọbu Sá kúrò lọ́dọ̀ Labani 1 Jakọbu gbọ́ pé àwọn ọmọ Labani ń sọ pé òun ti gba gbogbo ohun tíí ṣe ti baba wọn, ninu ohun ìní baba wọn…

JẸNẸSISI 32

Jakọbu Múra láti Pàdé Esau 1 Bí Jakọbu ti ń lọ ní ojú ọ̀nà, àwọn angẹli Ọlọrun pàdé rẹ̀. 2 Nígbà tí Jakọbu rí wọn, ó ní, “Àwọn ọmọ ogun…

JẸNẸSISI 33

Jakọbu Pàdé Esau 1 Bí Jakọbu ti gbé ojú sókè, ó rí Esau tí ń bọ̀ pẹlu irinwo (400) ọkunrin. Ó bá pín àwọn ọmọ rẹ̀ fún Lea ati Rakẹli,…

JẸNẸSISI 34

Wọ́n fi Ipá bá Dina Lòpọ̀ 1 Ní ọjọ́ kan, Dina, ọmọbinrin tí Lea bí fún Jakọbu jáde lọ kí àwọn obinrin kan ní ìlú Ṣekemu. 2 Nígbà tí Ṣekemu…

JẸNẸSISI 35

Ọlọrun Súre fún Jakọbu ní Bẹtẹli 1 Lẹ́yìn náà, Ọlọrun sọ fún Jakọbu pé, “Dìde, lọ sí Bẹtẹli kí o máa gbé ibẹ̀, kí o tẹ́ pẹpẹ kan fún Ọlọrun…

JẸNẸSISI 36

Àwọn Ìran Esau 1 Àkọsílẹ̀ ìran Esau, tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Edomu nìyí: 2 Ninu àwọn ọmọbinrin Kenaani ni Esau ti fẹ́ aya, ekinni ń jẹ́ Ada, ọmọ Eloni…

JẸNẸSISI 37

Josẹfu ati Àwọn Arakunrin Rẹ̀ 1 Jakọbu ń gbé ilẹ̀ Kenaani, níbi tí àwọn baba rẹ̀ ti ṣe àtìpó. 2 Àkọsílẹ̀ ìran Jakọbu nìyí: Josẹfu jẹ́ ọmọ ọdún mẹtadinlogun ó…

JẸNẸSISI 38

Juda ati Tamari 1 Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà ni Juda bá fi àwọn arakunrin rẹ̀ sílẹ̀, ó kó lọ sí ọ̀dọ̀ ará Adulamu kan tí wọn ń pè ní…

JẸNẸSISI 39

Josẹfu ati Aya Pọtifari 1 Àwọn ará Iṣimaeli mú Josẹfu lọ sí Ijipti, wọ́n sì tà á fún Pọtifari ará Ijipti. Pọtifari yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ìjòyè Farao, òun…

JẸNẸSISI 40

Josẹfu Túmọ̀ Àlá Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Meji 1 Ní àkókò kan, agbọ́tí Farao, ọba Ijipti, ati olórí alásè rẹ̀ ṣẹ ọba. 2 Inú bí Farao sí àwọn iranṣẹ rẹ̀ mejeeji yìí,…