NEHEMAYA 8
Ẹsira Ka Òfin fún Àwọn Eniyan náà 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù náà, gbogbo wọn pátá péjọ pọ̀ sí gbangba ìta níwájú Ẹnubodè Omi, wọ́n sì sọ fún Ẹsira, akọ̀wé,…
Ẹsira Ka Òfin fún Àwọn Eniyan náà 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù náà, gbogbo wọn pátá péjọ pọ̀ sí gbangba ìta níwájú Ẹnubodè Omi, wọ́n sì sọ fún Ẹsira, akọ̀wé,…
Àwọn Eniyan náà Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Wọn 1 Ní ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kan náà, àwọn ọmọ Israẹli péjọ pọ̀, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀, wọ́n sì ku eruku sí orí…
1 Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya. 2 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ alufaa wọnyi:…
Àwọn Eniyan Tí Wọn Ń Gbé Jerusalẹmu 1 Àwọn olórí àwọn eniyan náà ń gbé Jerusalẹmu, àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù dìbò láti yan ẹnìkọ̀ọ̀kan ninu eniyan mẹ́wàá mẹ́wàá láti lọ…
Orúkọ Àwọn Alufaa ati Àwọn Ọmọ Lefi 1 Orúkọ àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n bá Serubabeli ọmọ Ṣealitieli ati Jeṣua dé nìwọ̀nyí: Seraaya, Jeremaya ati Ẹsira, 2…
Yíyẹra Kúrò lára Àwọn Àjèjì 1 Ní ọjọ́ náà, wọ́n kà ninu ìwé Mose sí etígbọ̀ọ́ àwọn eniyan, ibẹ̀ sì ni a ti rí i kà pé àwọn ará Amoni…
Ayaba Faṣiti Rí Ahasu-erusi Ọba Fín 1 Ní àkókò tí Ahasu-erusi jọba ní ilẹ̀ Pasia, ìjọba rẹ̀ tàn dé agbègbè mẹtadinlaadoje (127), láti India títí dé Kuṣi ní ilẹ̀ Etiopia….
Ẹsita Di Ayaba 1 Nígbà tí ó yá, tí ibinu ọba rọlẹ̀, ó ranti ohun tí Faṣiti ṣe, ati àwọn àṣẹ tí òun pa nípa rẹ̀. 2 Àwọn iranṣẹ ọba…
Hamani Dìtẹ̀ láti Pa Àwọn Juu Run 1 Ahasu-erusi ọba gbé Hamani, ọmọ Hamedata, ará Agagi, ga ju gbogbo àwọn ìjòyè yòókù lọ. 2 Gbogbo àwọn olóyè ní ẹnu ọ̀nà…
Modekai Wá Ìrànlọ́wọ́ Ẹsita 1 Nígbà tí Modekai gbọ́ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó fa aṣọ rẹ̀ ya. Ó fi àkísà ati eérú bo ara rẹ̀. Ó kígbe lọ…