JOBU 5

1 “Pe ẹnìkan nisinsinyii; ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni dá ọ lóhùn? Ẹni mímọ́ wo ni o lè tọ̀ lọ? 2 Dájúdájú ibinu a máa pa òmùgọ̀, owú jíjẹ a sì máa pa…

JOBU 6

1 Jobu bá dáhùn pé, 2 “Bí ó bá ṣeéṣe láti wọn ìbànújẹ́ mi, tí a bá sì le gbé ìdààmú mi lé orí ìwọ̀n, 3 ìbá wúwo ju yanrìn…

JOBU 7

1 “Ìgbésí ayé eniyan le koko, ọjọ́ ayé rẹ̀ sì dàbí ti alágbàṣe. 2 Ó dàbí ẹrú tí ń wá ìbòòji kiri ati bí alágbàṣe tí ń dúró de owó…

JOBU 8

1 Bilidadi ará Ṣuha dáhùn pé, 2 “O óo ti sọ irú ọ̀rọ̀ wọnyi pẹ́ tó, tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ yóo sì dàbí afẹ́fẹ́ líle? 3 Ṣé Ọlọrun a máa…

JOBU 9

1 Jobu dáhùn pé: 2 “Lóòótọ́, mo mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí, ṣugbọn báwo ni ẹlẹ́ran ara ṣe lè jẹ́ olódodo níwájú Ọlọrun? 3 Bí eniyan tilẹ̀ fẹ́ bá…

JOBU 10

1 “Ayé sú mi, nítorí náà n kò ní dákẹ́ ìráhùn; n óo sọ̀rọ̀ pẹlu ìbànújẹ́ ọkàn. 2 N óo sọ fún Ọlọrun pé kí ó má dá mi lẹ́bi;…

JOBU 11

1 Sofari ará Naama dáhùn pé, 2 “Ǹjẹ́ ó dára kí eniyan sọ ọpọlọpọ ọ̀rọ̀ kalẹ̀ báyìí kí ó má sì ìdáhùn? Àbí, ṣé ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ lè mú kí á…

JOBU 12

1 Jobu dáhùn pé: 2 “Láìsí àní àní, ẹ̀yin ni agbẹnusọ gbogbo eniyan, bí ẹ bá jáde láyé, ọgbọ́n kan kò tún ní sí láyé mọ́. 3 Bí ẹ ti…

JOBU 13

1 “Gbogbo ìwọ̀nyí ni ojú mi ti rí rí, tí etí mi ti gbọ́, tí ó sì yé mi. 2 Ohun tí ẹ mọ̀ wọnyi, èmi náà mọ̀ ọ́n, ẹ…

JOBU 14

1 “Ẹnikẹ́ni tí obinrin bá bí, ọlọ́jọ́ kúkúrú ni, ó sì kún fún ìpọ́njú. 2 Yóo kọ́ yọ bí òdòdó, lẹ́yìn náà yóo sì rẹ̀ dànù. Yóo kọjá lọ bí…