JOBU 35

1 Elihu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ bọ̀, ó ní, 2 “Jobu, ṣé o rò pé ó tọ̀nà, kí o máa sọ pé, ‘Ọ̀nà mi tọ́ níwájú Ọlọrun?’ 3 Kí…

JOBU 36

1 Elihu tún tẹ̀síwájú ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní, 2 “Ní sùúrù fún mi díẹ̀, n óo ṣe àlàyé fún ọ, nítorí mo ní ohun kan tí mo fẹ́ gbẹnusọ…

JOBU 37

1 “Nígbà tí mo gbọ́, ọkàn mi wárìrì, ó sì fò sókè ní ipò rẹ̀. 2 Gbọ́ ohùn rẹ̀ tí ń dún bí ààrá, ati ariwo tí ń ti ẹnu…

JOBU 38

OLUWA dá Jobu Lóhùn 1 Nígbà náà ni OLUWA dá Jobu lóhùn láti inú ìjì líle. 2 Ó bi í pé, “Ta ni ẹni tí ń bu ẹnu àtẹ́ lu…

JOBU 39

1 “Ǹjẹ́ o mọ ìgbà tí àwọn ewúrẹ́ orí àpáta ń bímọ? Ṣé o ti ká àgbọ̀nrín mọ́ ibi tí ó ti ń bímọ rí? 2 Ǹjẹ́ o lè ka…

JOBU 40

1 OLUWA tún sọ fún Jobu pé, 2 “Ṣé ẹni tí ń bá eniyan rojọ́ lè bá Olodumare rojọ́? Kí ẹni tí ń bá Ọlọrun jiyàn dáhùn.” 3 Nígbà náà…

JOBU 41

1 “Ṣé o lè fi ìwọ̀ fa Lefiatani jáde, tabi kí o fi okùn di ahọ́n rẹ̀? 2 Ṣé o lè fi okùn sí imú rẹ̀, tabi kí o fi…

JOBU 42

1 Jobu bá dá OLUWA lóhùn ó ní: 2 “Mo mọ̀ pé o lè ṣe ohun gbogbo, kò sì sí ohun tí ó lè da ìpinnu rẹ rú. 3 Ta…

ORIN DAFIDI 1

Ayọ̀ Tòótọ́ 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni náà tí kò gba ìmọ̀ràn àwọn eniyan burúkú, tí kò bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ rìn, tí kò sì bá àwọn ẹlẹ́gàn kẹ́gbẹ́. 2…

ORIN DAFIDI 2

Àyànfẹ́ Ọlọrun 1 Kí ló dé tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń bínú fùfù tí àwọn eniyan ń gbìmọ̀ asán? 2 Àwọn ọba ayé kó ara wọn jọ, àwọn ìjòyè gbìmọ̀…