JẸNẸSISI 41

Josẹfu Túmọ̀ Àlá Ọba 1 Lẹ́yìn ọdún meji gbáko, Farao náà wá lá àlá pé òun dúró létí odò Naili. 2 Ó rí àwọn mààlúù meje kan tí wọ́n sanra…

JẸNẸSISI 42

Àwọn Arakunrin Josẹfu Lọ Ra Ọkà ní Ijipti 1 Nígbà tí Jakọbu gbọ́ pé ọkà wà ní ilẹ̀ Ijipti, ó wí fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé, “Kí ni ẹ̀ ń…

JẸNẸSISI 43

Àwọn Arakunrin Josẹfu Pada Lọ sí Ijipti pẹlu Bẹnjamini 1 Ìyàn tí ó mú ní ilẹ̀ Kenaani ṣá túbọ̀ ń pọ̀ sí i ni. 2 Nígbà tí wọ́n jẹ ọkà…

JẸNẸSISI 44

Ife Tí Ó Sọnù 1 Josẹfu pàṣẹ fún alabojuto ilé rẹ̀, ó ní, “Ẹ di ọkà kún àpò àwọn ọkunrin wọnyi, bí wọ́n bá ti lè rù tó, kí ẹ…

JẸNẸSISI 45

Josẹfu Farahan Àwọn Arakunrin Rẹ̀ 1 Josẹfu kò lè mú ọ̀rọ̀ yìí mọ́ra mọ́ lójú gbogbo àwọn tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀, ó bá kígbe, ó ní, “Gbogbo yín patapata,…

JẸNẸSISI 46

Jakọbu ati Ìdílé Rẹ̀ Lọ sí Ijipti 1 Israẹli di gbogbo ohun tí ó ní, ó kó lọ sí Beeriṣeba, ó lọ rúbọ sí Ọlọrun Isaaki, baba rẹ̀. 2 Ọlọrun…

JẸNẸSISI 47

1 Josẹfu bá wọlé lọ sọ fún Farao pé, “Baba mi ati àwọn arakunrin mi ti dé láti ilẹ̀ Kenaani, pẹlu gbogbo agbo ẹran ati agbo mààlúù wọn, ati ohun…

JẸNẸSISI 48

Jakọbu Súre fún Efuraimu ati Manase 1 Lẹ́yìn náà, wọ́n sọ fún Josẹfu pé ara baba rẹ̀ kò yá, Josẹfu bá mú àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeji, Manase ati Efuraimu, lọ́wọ́…

JẸNẸSISI 49

Ọ̀rọ̀ Ìkẹyìn Jakọbu 1 Jakọbu ranṣẹ pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó wí fún wọn pé, “Ẹ kó ara yín jọ kí n lè sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ si yín…

JẸNẸSISI 50

1 Josẹfu dojúbo òkú baba rẹ̀ lójú, ó sọkún, ó sì fi ẹnu kò ó lẹ́nu. 2 Lẹ́yìn náà, Josẹfu pàṣẹ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ tí wọn ń ṣiṣẹ́ ìṣègùn…