ORIN DAFIDI 13
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni? Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi? 2 Títí…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni? Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi? 2 Títí…
Èrè Òmùgọ̀ 1 Òmùgọ̀ sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé, “Ọlọrun kò sí.” Wọ́n bàjẹ́, ohun ìríra ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn, kò sì sí ẹnìkan ninu wọn tí ń ṣe rere….
Ìwà tí Ọlọrun Fẹ́ 1 OLUWA, ta ni ó lè máa gbé inú àgọ́ rẹ? Ta ni ó lè máa gbé orí òkè mímọ́ rẹ? 2 Ẹni tí ń rìn…
Mo Sá di OLUWA 1 Pa mí mọ́ Ọlọrun, nítorí ìwọ ni mo sá di. 2 Mo wí fún ọ, OLUWA, pé, “Ìwọ ni Oluwa mi; ìwọ nìkan ni orísun…
Adura fún Ìdáláre 1 Gbọ́ tèmi OLUWA, àre ni ẹjọ́ mi; fi ìtara gbọ́ igbe mi. Fetí sí adura mi nítorí kò sí ẹ̀tàn ní ẹnu mi. 2 Jẹ́ kí…
Orin Ìṣẹ́gun 1 Mo fẹ́ràn rẹ, OLUWA, agbára mi. 2 OLUWA ni àpáta mi, ibi ààbò mi, ati olùgbàlà mi; Ọlọrun mi, àpáta mi, ninu ẹni tí ààbò mi wà….
Ògo Ọlọrun ninu àwọn ohun tí Ó dá 1 Ojú ọ̀run ń sọ̀rọ̀ ògo Ọlọrun, òfuurufú sì ń kéde iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀. 2 Ọjọ́ dé ọjọ́ ń sọ ọ́ ní…
Adura Ìṣẹ́gun 1 OLUWA óo dá ọ lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú, orúkọ Ọlọrun Jakọbu óo dáàbò bò ọ́. 2 Yóo rán olùrànlọ́wọ́ sí ọ láti ilé mímọ́ rẹ̀ wá, yóo…
Orin Ìṣẹ́gun 1 Ọba ń yọ̀ nítorí agbára rẹ, OLUWA; inú rẹ̀ ń dùn lọpọlọpọ nítorí ríràn tí o ràn án lọ́wọ́! 2 O ti fún un ní ohun tí…
Igbe Ìrora ati Orin Ìyìn 1 Ọlọrun mi, Ọlọrun mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀, tí o fi jìnnà sí mi, tí o kò gbọ́ igbe…