ORIN DAFIDI 23
OLUWA ni Olùṣọ́ Mi 1 OLUWA ni Olùṣọ́-aguntan mi, n kò ní ṣe àìní ohunkohun. 2 Ó mú mi dùbúlẹ̀ ninu pápá koríko tútù, ó mú mi lọ sí ibi…
OLUWA ni Olùṣọ́ Mi 1 OLUWA ni Olùṣọ́-aguntan mi, n kò ní ṣe àìní ohunkohun. 2 Ó mú mi dùbúlẹ̀ ninu pápá koríko tútù, ó mú mi lọ sí ibi…
Ọba Atóbijù 1 OLUWA ló ni ilẹ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, òun ló ni ayé, ati gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀; 2 nítorí pé…
Adura fún ìtọ́sọ́nà ati Ààbò 1 OLUWA, ìwọ ni mo gbé ojú ẹ̀bẹ̀ sókè sí. 2 Ọlọrun mi, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé, má jẹ́ kí ojú ó tì mí; má…
Adura Ẹni Rere 1 Dá mi láre, OLUWA, nítorí ninu ìwà pípé ni mò ń rìn, mo sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA láìṣiyèméjì. 2 Yẹ̀ mí wò, OLUWA, dán mi wò; yẹ…
Adura Ìyìn 1 OLUWA ni ìmọ́lẹ̀ ati ìgbàlà mi; ta ni n óo bẹ̀rù? OLUWA ni ààbò ẹ̀mí mi, ẹ̀rù ta ni yóo bà mí? 2 Nígbà tí àwọn aṣebi…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Ìwọ ni mo kígbe pè, OLUWA, ìwọ ni ààbò mi, má di etí sí mi. Nítorí bí o bá dákẹ́ sí mi n óo dàbí àwọn òkú,…
Agbára OLUWA ninu ìjì 1 Ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run, ẹ fi ògo fún OLUWA, ẹ gbé agbára rẹ̀ lárugẹ. 2 Ẹ fún OLUWA ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀, ẹ…
Adura Ọpẹ́ 1 N óo yìn ọ́, OLUWA, nítorí pé o ti yọ mí jáde; o kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí. 2 OLUWA, Ọlọrun mi,…
Adura Igbẹkẹle Ọlọrun 1 OLUWA, ìwọ ni mo sá di, má jẹ́ kí ojú tì mí lae; gbà mí, nítorí olóòótọ́ ni ọ́. 2 Dẹ etí sí mi, yára gbà…
Ìjẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí a dárí ìrékọjá rẹ̀ jì, tí a bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀. 2 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí OLUWA kò ka…