ORIN DAFIDI 43
Adura Ẹni tí A Lé ní Ìlú 1 Dá mi láre, Ọlọrun, kí o sì gbèjà mi, lọ́dọ̀ àwọn tí kò mọ̀ Ọ́; gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn ati alaiṣootọ….
Adura Ẹni tí A Lé ní Ìlú 1 Dá mi láre, Ọlọrun, kí o sì gbèjà mi, lọ́dọ̀ àwọn tí kò mọ̀ Ọ́; gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn ati alaiṣootọ….
Adura Ààbò 1 Ọlọrun, a ti fi etí wa gbọ́, àwọn baba wa sì ti sọ fún wa, nípa àwọn ohun tí o ṣe nígbà ayé wọn, àní, ní ayé…
Orin Igbeyawo Ọmọ Ọba 1 Èrò rere kan ń gbé mi lọ́kàn, mò ń kọ orin mi fún ọba ahọ́n mi dàbí gègé akọ̀wé tó mọṣẹ́. 2 Ìwọ ni o…
Ọlọrun Wà pẹlu Wa 1 Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa, olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú. 2 Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí…
Ọba Àwọn Ọba 1 Ẹ pàtẹ́wọ́, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ kọ orin ayọ̀, ẹ hó sí Ọlọrun. 2 Nítorí pé ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ ni OLUWA, Ọ̀gá Ògo, Ọba ńlá lórí gbogbo…
OLUWA Tóbi 1 OLUWA tóbi, ó sì yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọ ní ìlú Ọlọrun wa. 2 Òkè mímọ́ rẹ̀, tí ó ga, tí ó sì lẹ́wà, ni…
Ìwà Òmùgọ̀ ni Igbẹkẹle Ọrọ̀ 1 Ẹ gbọ́, gbogbo orílẹ̀-èdè! Ẹ dẹtí sílẹ̀, gbogbo aráyé, 2 ati mẹ̀kúnnù àtọlọ́lá, àtolówó ati talaka! 3 Ẹnu mi yóo sọ̀rọ̀ ọgbọ́n; àṣàrò ọkàn…
Ìsìn Tòótọ́ 1 OLUWA, Ọlọrun Alágbára ti sọ̀rọ̀: ó ké sí gbogbo ayé láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ oòrùn. 2 Ọlọrun yọ bí ọjọ́ láti Sioni, ìlú tó dára,…
Adura Ìdáríjì 1 Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ pa ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́. 2 Wẹ̀ mí mọ́ kúrò ninu àìdára mi, kí…
Ìdájọ́ ati Oore Ọ̀fẹ́ Ọlọrun 1 Ìwọ alágbára, kí ló dé tí o fi ń fọ́nnu, kí ló dé tí ò ń fọ́nnu tọ̀sán-tòru? Ẹni ìtìjú ni ọ́ lójú Ọlọrun….