ORIN DAFIDI 53

Èrè Òmùgọ̀ 1 Òmùgọ̀ sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé, “Kò sí Ọlọrun.” Wọ́n bàjẹ́, ohun ìríra ni wọ́n ń ṣe, kò sì sí ẹnìkan ninu wọn tí ń ṣe rere….

ORIN DAFIDI 54

Adura Ààbò 1 Fi agbára orúkọ rẹ gbà mí, Ọlọrun, fi ipá rẹ dá mi láre. 2 Gbọ́ adura mi, Ọlọrun; tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ẹnu mi. 3 Nítorí pé àwọn…

ORIN DAFIDI 55

Adura Ẹni tí Ọ̀rẹ́ Dà 1 Tẹ́tí sí adura mi, Ọlọrun, má sì fara pamọ́ nígbà tí mo bá ń bẹ̀bẹ̀. 2 Fetí sí mi, kí o sì dá mi…

ORIN DAFIDI 56

Adura Igbẹkẹle Ọlọrun 1 Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí pé àwọn eniyan ń lépa mi; ọ̀tá gbógun tì mí tọ̀sán-tòru. 2 Àwọn ọ̀tá ń lépa mi tọ̀sán-tòru, ọpọlọpọ ní ń bá…

ORIN DAFIDI 57

Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Ṣàánú mi, Ọlọrun, ṣàánú mi, nítorí ìwọ ni ààbò mi; abẹ́ òjìji apá rẹ ni n óo fi ṣe ààbò mi, títí gbogbo àjálù wọnyi yóo fi…

ORIN DAFIDI 58

Kí Ọlọrun jẹ Ìkà níyà 1 Ǹjẹ́ ìpinnu tí ẹ̀ ń ṣe tọ̀nà, ẹ̀yin aláṣẹ? Ǹjẹ́ ẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan ní ọ̀nà ẹ̀tọ́? 2 Rárá o! Ibi ni…

ORIN DAFIDI 59

Adura Ààbò 1 Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Ọlọrun mi; dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn tí ó gbógun tì mí. 2 Gbà mí lọ́wọ́ àwọn aṣebi, kí o sì…

ORIN DAFIDI 60

Adura fún Ìgbàlà 1 Ọlọrun, o ti kọ̀ wá sílẹ̀, o ti wó odi wa; o ti bínú, dákun, mú wa bọ̀ sípò. 2 O ti mú kí ilẹ̀ mì…

ORIN DAFIDI 61

Adura Ààbò 1 Gbọ́ igbe mi, Ọlọrun, fetí sí adura mi. 2 Láti ọ̀nà jíjìn réré ni mo ti ké pè ọ́, nígbà tí àárẹ̀ mú mi. Tọ́ mi lọ…

ORIN DAFIDI 62

Ọlọrun ni Ààbò Wa 1 Ọlọrun nìkan ni mo fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé; ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá. 2 Òun nìkan ni àpáta ati olùgbàlà mi, òun ni odi…