ORIN DAFIDI 63

Wíwá Ọlọrun 1 Ọlọrun, ìwọ ni Ọlọrun mi, mò ń wá ọ, ọkàn rẹ ń fà mí; bí ilẹ̀ tí ó ti ṣá, tí ó sì gbẹ ṣe máa ń…

ORIN DAFIDI 64

Adura Ààbò 1 Ọlọrun, gbọ́ ìráhùn mi; pa mí mọ́ lọ́wọ́ ìdẹ́rùbà ọ̀tá; 2 dáàbò bò mí lọ́wọ́ ọ̀tẹ̀ àwọn eniyan burúkú; kó mi yọ lọ́wọ́ ète àwọn aṣebi. 3…

ORIN DAFIDI 65

Ìyìn ati Ọpẹ́ 1 Ọlọrun, ìwọ ni ìyìn yẹ ní Sioni, ìwọ ni a óo san ẹ̀jẹ́ wa fún, 2 ìwọ tí ń gbọ́ adura! Ọ̀dọ̀ rẹ ni gbogbo eniyan…

ORIN DAFIDI 66

Orin Ìyìn ati Ọpẹ́ 1 Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun. 2 Ẹ kọ orin ògo yin orúkọ rẹ̀; ẹ yìn ín, ẹ fògo fún un! 3 Ẹ…

ORIN DAFIDI 67

Orin Ọpẹ́ 1 Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa; kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára; 2 kí gbogbo ayé lè mọ ọ̀nà rẹ̀; kí gbogbo…

ORIN DAFIDI 68

Orin ìṣẹ́gun ti Orílẹ̀-Èdè 1 Kí Ọlọrun dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ tú ká. Kí àwọn tí ó kórìíra rẹ̀ sá níwájú rẹ̀. 2 Bí èéfín tií pòórá, bẹ́ẹ̀ ni…

ORIN DAFIDI 69

Igbe fún Ìrànlọ́wọ́ 1 Gbà mí, Ọlọrun, nítorí omi ti mù mí dé ọrùn. 2 Mo ti rì sinu irà jíjìn, níbi tí kò ti sí ohun ìfẹsẹ̀tẹ̀; mo ti…

ORIN DAFIDI 70

Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 Ọlọrun, dákun, gbà mí, yára, OLUWA, ràn mí lọ́wọ́. 2 Jẹ́ kí ojú ti gbogbo àwọn tí wọn fẹ́ gba ẹ̀mí mi kí ìdàrúdàpọ̀ bá wọn; jẹ́…

ORIN DAFIDI 71

Adura Àgbàlagbà kan 1 OLUWA, ìwọ ni mo sá di; má jẹ́ kí ojú ó tì mí laelae! 2 Gbà mí, kí o sì yọ mí nítorí òdodo rẹ; tẹ́tí…

ORIN DAFIDI 72

Adura Ọba 1 Ọlọrun, gbé ìlànà òtítọ́ rẹ lé ọba lọ́wọ́; kọ́ ọmọ ọba ní ọ̀nà òdodo rẹ. 2 Kí ó lè máa fi òdodo ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan rẹ,…