ORIN DAFIDI 103
Ìfẹ́ Ọlọrun 1 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, fi tinútinú yin orúkọ rẹ̀ mímọ́. 2 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, má sì ṣe gbàgbé gbogbo oore rẹ̀, 3 ẹni tí…
Ìfẹ́ Ọlọrun 1 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, fi tinútinú yin orúkọ rẹ̀ mímọ́. 2 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, má sì ṣe gbàgbé gbogbo oore rẹ̀, 3 ẹni tí…
Yíyin Ẹlẹ́dàá 1 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, OLUWA, Ọlọrun mi, ó tóbi pupọ, ọlá ati iyì ni ó wọ̀ bí ẹ̀wù. 2 Ó fi ìmọ́lẹ̀ bora bí aṣọ, ó…
Ọlọrun ati Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè. 2 Ẹ kọrin sí i, ẹ kọ orin…
Oore OLUWA fún Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Ta…
Yíyin OLUWA fún Oore Rẹ̀ 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Kí àwọn tí OLUWA ti…
Adura Ìrànlọ́wọ́ láti Borí Ọ̀tá 1 Ọkàn mi dúró ṣinṣin, Ọlọrun ọkàn mi dúró ṣinṣin. N óo kọrin, n óo sì máa yìn ọ́. Jí, ìwọ ọkàn mi! 2 Ẹ…
Ìráhùn Ẹni tí Ó Wà ninu Ìṣòro 1 Má dákẹ́, ìwọ Ọlọrun tí mò ń yìn. 2 Nítorí pé ẹnu àwọn eniyan burúkú ati ti àwọn ẹlẹ́tàn kò dákẹ́, wọ́n…
OLUWA ati Àyànfẹ́ Ọba Rẹ̀ 1 OLUWA wí fún oluwa mi, ọba, pé, “Jókòó sí apá ọ̀tún mi, títí tí n óo fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ìtìsẹ̀…
Yin OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! N óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tọkàntọkàn, láàrin àwọn olódodo, ati ní àwùjọ àwọn eniyan. 2 Iṣẹ́ OLUWA tóbi, àwọn tí ó nífẹ̀ẹ́ sí i…
Ayọ̀ Ẹni Rere 1 Ẹ yin OLUWA! Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bẹ̀rù OLUWA, tí inú rẹ̀ sì dùn lọpọlọpọ sí òfin rẹ̀. 2 Àwọn arọmọdọmọ rẹ̀ yóo…