ORIN DAFIDI 113
Yíyin OLUWA fún Oore Rẹ̀ 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yìn ín, ẹ̀yin iranṣẹ OLUWA. Ẹ yin orúkọ OLUWA. 2 Kí á yin orúkọ OLUWA, láti ìsinsìnyìí lọ títí laelae….
Yíyin OLUWA fún Oore Rẹ̀ 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yìn ín, ẹ̀yin iranṣẹ OLUWA. Ẹ yin orúkọ OLUWA. 2 Kí á yin orúkọ OLUWA, láti ìsinsìnyìí lọ títí laelae….
Orin Ìrékọjá 1 Nígbà tí Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, tí àwọn ọmọ Jakọbu jáde kúrò láàrin àwọn tí ń sọ èdè àjèjì, 2 Juda di ilé mímọ́ rẹ̀,…
Ọlọrun Òdodo 1 Ògo kì í ṣe fún wa, OLUWA, Kì í ṣe fún wa, orúkọ rẹ nìkan ṣoṣo ni kí á yìn lógo, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í…
Orin Ọpẹ́ 1 Mo fẹ́ràn OLUWA nítorí pé ó gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ mi. 2 Nítorí pé ó tẹ́tí sí mi, nítorí náà, n óo máa ké pè é níwọ̀n…
Yíyin OLUWA 1 Ẹ máa yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè! Ẹ yìn ín gbogbo ẹ̀yin eniyan, 2 Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tóbi sí wa, òtítọ́ rẹ̀ sì…
Adura Ọpẹ́ fún Ìṣẹ́gun 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Jẹ́ kí Israẹli wí pé,…
Òfin OLUWA 1 Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ìgbé ayé wọn kò lábàwọ́n, àní àwọn tí ń rìn gẹ́gẹ́ bí òfin OLUWA. 2 Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 OLUWA ni mo ké pè, nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú, ó sì dá mi lóhùn. 2 OLUWA, gbà mí lọ́wọ́ àwọn èké, ati lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn….
OLUWA Aláàbò Wa 1 Mo gbójú sókè wo àwọn òkè, níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá? 2 Ìrànlọ́wọ́ mi ń ti ọ̀dọ̀ OLUWA wá, ẹni tí ó dá ọ̀run…
Ìyìn Jerusalẹmu 1 Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ sí ilé OLUWA.” 2 A ti tẹsẹ̀ bọ inú ìgboro rẹ, Jerusalẹmu….