ORIN DAFIDI 123

Adura Àánú 1 Ìwọ ni mo gbé ojú sókè sí, ìwọ tí o gúnwà ní ọ̀run. 2 Wò ó, bí iranṣẹkunrin ti máa ń wo ojú oluwa rẹ̀, tí iranṣẹbinrin…

ORIN DAFIDI 124

Ọlọrun Aláàbò Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ wí pé, 2 “Tí kì í bá ṣe…

ORIN DAFIDI 125

Ìfọ̀kànbalẹ̀ Àwọn Eniyan OLUWA 1 Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA dàbí òkè Sioni, tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí nídìí, ṣugbọn tí ó wà títí lae. 2 Bí òkè ńlá ti…

ORIN DAFIDI 126

Ẹkún Di Ayọ̀ 1 Nígbà tí OLUWA kó àwọn ìgbèkùn Sioni pada, ó dàbí àlá lójú wa. 2 Ẹ̀rẹ̀kẹ́ wa kún fún ẹ̀rín, a sì kọrin ayọ̀, nígbà náà ni…

ORIN DAFIDI 127

Abániṣé ni OLUWA 1 Bí OLUWA kò bá kọ́ ilé, asán ni wahala àwọn tí ń kọ́ ọ. Bí OLUWA kò bá ṣọ́ ìlú, asán ni àìsùn àwọn aṣọ́de. 2…

ORIN DAFIDI 128

Ìbẹ̀rù OLUWA lérè 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bẹ̀rù OLÚWA, tí ó sì ń tẹ̀lé ìlànà rẹ̀. 2 O óo jèrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ, ayọ̀ ń bẹ…

ORIN DAFIDI 129

Kí ojú ti ọ̀tá 1 Ọpọlọpọ ìgbà ni wọ́n ti ń pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi. Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ wí pé, 2 “Ọpọlọpọ ìgbà ni wọ́n ti…

ORIN DAFIDI 130

Adura Ẹlẹ́ṣẹ̀ 1 Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA! 2 OLUWA, gbóhùn mi, dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. 3 Bí OLUWA bá ń sàmì ẹ̀ṣẹ̀, ta…

ORIN DAFIDI 131

Àṣírí ìfọ̀kànbalẹ̀ 1 OLUWA, n kò ṣe ìgbéraga, bẹ́ẹ̀ ni ojú mi kò gbé sókè. N ò dáwọ́ lé nǹkan ńláńlá, n ò sì dá àrà tí ó jù mí…

ORIN DAFIDI 132

Majẹmu Ọlọrun pẹlu Ìdílé Dafidi 1 OLUWA, ranti gbogbo ìyà tí Dafidi fara dà. 2 Ranti bí ó ṣe búra fún OLUWA, tí ó sì jẹ́jẹ̀ẹ́ fún ìwọ Alágbára, Ọlọrun…