ORIN DAFIDI 143
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 OLUWA, gbọ́ adura mi; fetí sí ẹ̀bẹ̀ mi! Dá mi lóhùn ninu òtítọ́ ati òdodo rẹ. 2 Má dá èmi ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ lẹ́jọ́, nítorí pé kò sí…
Adura Ìrànlọ́wọ́ 1 OLUWA, gbọ́ adura mi; fetí sí ẹ̀bẹ̀ mi! Dá mi lóhùn ninu òtítọ́ ati òdodo rẹ. 2 Má dá èmi ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ lẹ́jọ́, nítorí pé kò sí…
Ọpẹ́ fún Ìṣẹ́gun 1 Ìyìn ni fún OLUWA, àpáta mi, ẹni tí ó kọ́ mi ní ìjà jíjà, tí ó kọ́ mi ní iṣẹ́ ogun. 2 Òun ni àpáta mi,…
Orin Ìyìn 1 Èmi óo gbé ọ ga, Ọlọrun mi, Ọba mi, n óo máa yin orúkọ rẹ lae ati laelae. 2 Lojoojumọ ni n óo máa yìn ọ́, tí…
Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi. 2 N óo máa yin OLUWA níwọ̀n ìgbà tí mo wà láyé; n óo máa kọrin ìyìn sí Ọlọrun…
Ọlọrun Alágbára 1 Ẹ yin OLUWA! Nítorí tí ó dára láti máa kọ orin ìyìn sí Ọlọrun wa; nítorí olóore ni, orin ìyìn sì yẹ ẹ́. 2 OLUWA ní ń…
Kí gbogbo ẹ̀dá Yin OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin OLUWA, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run, ẹ yìn ín lókè ọ̀run. 2 Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin angẹli rẹ̀; ẹ yìn…
Orin Ìyìn sí OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́. 2 Kí Israẹli máa yọ̀ ninu Ẹlẹ́dàá…
Ẹ yin OLUWA 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀; ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára. 2 Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá…
Anfaani Àwọn Òwe 1 Àwọn òwe tí Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli pa, 2 kí àwọn eniyan lè ní ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́, kí òye ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lè yé wọn, 3…
Èrè Tó Wà ninu Ọgbọ́n 1 Ọmọ mi, bí o bá gba ọ̀rọ̀ mi, tí o sì pa òfin mi mọ́, 2 tí o bá ń tẹ́tí rẹ sílẹ̀ sí…