ÌWÉ ÒWE 3

Ìmọ̀ràn fún Àwọn Ọ̀dọ́ 1 Ọmọ mi, má ṣe gbàgbé ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ ọ, sì pa òfin mi mọ́ lọ́kàn rẹ, 2 nítorí wọn óo fún ọ ní ẹ̀mí…

ÌWÉ ÒWE 4

Anfaani Tí Ó Wà ninu Ọgbọ́n 1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ gbọ́ ẹ̀kọ́ baba yín, ẹ tẹ́tí sílẹ̀, kí ẹ lè ní ìmọ̀, 2 nítorí pé mo fun yín ní ìlànà…

ÌWÉ ÒWE 5

Ìkìlọ̀ nípa Àgbèrè 1 Ọmọ mi fetí sí ọgbọ́n tí mò ń kọ́ ọ, tẹ́tí rẹ sí òye mi, 2 kí o baà lè ní làákàyè, kí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ…

ÌWÉ ÒWE 6

Àwọn Ìkìlọ̀ Mìíràn 1 Ọmọ mi, bí o bá ṣe onídùúró fún aládùúgbò rẹ, tí o jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún àjèjì, 2 tí o bá bọ́ sinu tàkúté tí o fi…

ÌWÉ ÒWE 7

1 Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, kí o sì fi òfin mi sinu ọkàn rẹ. 2 Pa òfin mi mọ́, kí o lè yè, pa ẹ̀kọ́ mi mọ́ gẹ́gẹ́…

ÌWÉ ÒWE 8

Yíyin Ọgbọ́n 1 Ọgbọ́n ń pe eniyan, òye ń pariwo. 2 Ó dúró ní ibi tí ó ga lẹ́bàá ọ̀nà, ati ní ojú ọ̀nà tóóró, 3 ó ń kígbe lóhùn…

ÌWÉ ÒWE 9

Ọgbọ́n ati Wèrè 1 Ọgbọ́n ti kọ́lé, ó ti gbé àwọn òpó rẹ̀ mejeeje nàró. 2 Ó ti pa ẹran rẹ̀, ó ti pọn ọtí waini rẹ̀, ó sì ti…

ÌWÉ ÒWE 10

Àwọn Òwe Solomoni 1 Àwọn òwe Solomoni nìwọ̀nyí: Ọlọ́gbọ́n ọmọ á máa mú kí inú baba rẹ̀ dùn, ṣugbọn òmùgọ̀ ọmọ a máa kó ìbànújẹ́ bá ìyá rẹ̀. 2 Ọrọ̀…

ÌWÉ ÒWE 11

1 OLUWA kórìíra òṣùnwọ̀n èké, òṣùnwọ̀n tí ó péye ni inú rẹ̀ dùn sí. 2 Bí ìgbéraga bá wọlé, àbùkù a tẹ̀lé e, ṣugbọn ọgbọ́n wà pẹlu àwọn onírẹ̀lẹ̀. 3…

ÌWÉ ÒWE 12

1 Ẹni tí ó fẹ́ ìtọ́sọ́nà, ó fẹ́ ìmọ̀, ṣugbọn ẹni tí ó kórìíra ìbáwí òmùgọ̀ ni. 2 Eniyan rere a máa ní ojurere lọ́dọ̀ OLUWA, ṣugbọn ẹni tí ń…