ÌWÉ ÒWE 13

1 Ọlọ́gbọ́n ọmọ a máa gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀, ṣugbọn ẹlẹ́yà kì í gbọ́ ìbáwí. 2 Eniyan rere a máa rí ire nítorí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀, ṣugbọn ohun tí àwọn…

ÌWÉ ÒWE 14

1 Ọlọ́gbọ́n obinrin a máa kọ́ ilé rẹ̀, ṣugbọn òmùgọ̀ a máa fi ọwọ́ ara rẹ̀ tú tirẹ̀ palẹ̀. 2 Ẹni tí ń rìn pẹlu òótọ́ inú yóo bẹ̀rù OLUWA,…

ÌWÉ ÒWE 15

1 Ìdáhùn pẹ̀lẹ́ a máa mú kí ibinu rọlẹ̀, ṣugbọn ọ̀rọ̀ líle níí ru ibinu sókè. 2 Lẹ́nu ọlọ́gbọ́n ni ọ̀rọ̀ ìmọ̀ ti ń jáde, ṣugbọn òmùgọ̀ a máa sọ̀rọ̀…

ÌWÉ ÒWE 16

1 Èrò ọkàn ni ti eniyan ṣugbọn OLUWA ló ni ìdáhùn. 2 Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó mọ́ lójú ara rẹ̀, ṣugbọn OLUWA ló rí ọkàn. 3 Fi gbogbo àdáwọ́lé…

ÌWÉ ÒWE 17

1 Kí á fi alaafia jẹun, láìsí ọbẹ̀, ó sàn ju kí á máa fi ẹran jẹun pẹlu ìyọnu lọ. 2 Ẹrú tí ó bá mọ ìwà hù, yóo di…

ÌWÉ ÒWE 18

1 Onímọ-tara-ẹni-nìkan ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀, láti tako ìdájọ́ òtítọ́. 2 Òmùgọ̀ kò ní inú dídùn sí ìmọ̀, àfi kí ó ṣá máa sọ èrò ọkàn rẹ̀. 3 Nígbà tí…

ÌWÉ ÒWE 19

1 Talaka tí ń rìn pẹlu òtítọ́ inú, ó sàn ju òmùgọ̀ eniyan, tí ó ń sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn lọ. 2 Kò dára kí eniyan wà láìní ìmọ̀, ẹni bá ń…

ÌWÉ ÒWE 20

1 Ẹlẹ́yà ni ọtí waini, aláriwo ní ọtí líle, ẹnikẹ́ni tí a bá fi tànjẹ kò gbọ́n. 2 Ibinu ọba dàbí bíbú kinniun, ẹni tí ó bá mú ọba bínú…

ÌWÉ ÒWE 21

1 Orísun omi ni ọkàn ọba lọ́wọ́ OLUWA, ibi tí ó bá wu Oluwa ni ó ń darí rẹ̀ sí. 2 Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó dára lójú ara rẹ̀,…

ÌWÉ ÒWE 22

1 Orúkọ rere dára láti yàn ju ọrọ̀ pupọ lọ, kí á rí ojurere sì dára ju kí á ní fadaka ati wúrà lọ. 2 Ọlọ́rọ̀ ati talaka pàdé, OLUWA…