ÌWÉ ÒWE 23
1 Nígbà tí o bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, kíyèsí ẹni tí ó bá wà níwájú rẹ dáradára. 2 Tí o bá jẹ́ wọ̀bìà eniyan, ṣọ́ra, kí o má…
1 Nígbà tí o bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, kíyèsí ẹni tí ó bá wà níwájú rẹ dáradára. 2 Tí o bá jẹ́ wọ̀bìà eniyan, ṣọ́ra, kí o má…
1 Má ṣe ìlara àwọn ẹni ibi, má sì ṣe bá wọn kẹ́gbẹ́, 2 nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ìparun, ẹnu wọn sì ń sọ̀rọ̀ ìkà. -20- 3 Ọgbọ́n ni…
Àwọn Òwe Mìíràn tí Solomoni Pa 1 Àwọn òwe mìíràn tí Solomoni pa, tí àwọn òṣìṣẹ́ Hesekaya ọba Juda kọ sílẹ̀ nìwọ̀nyí. 2 Ògo ni ó jẹ́ fún Ọlọrun láti…
1 Bí yìnyín kò ṣe yẹ ní àkókò ooru, ati òjò ní àkókò ìkórè, bẹ́ẹ̀ ni iyì kò yẹ òmùgọ̀. 2 Bí ológoṣẹ́ tí ń rábàbà kiri, ati bí alápàáǹdẹ̀dẹ̀…
1 Má lérí nípa ọ̀la, nítorí o kò mọ ohun tí ó lè ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan. 2 Ẹlòmíràn ni kí o jẹ́ kí ó yìn ọ́, má yin ara…
1 Àwọn eniyan burúkú a máa sá, nígbà tí ẹnikẹ́ni kò lé wọn, ṣugbọn olódodo a máa láyà bíi kinniun. 2 Bí orílẹ̀-èdè kan bá dẹ́ṣẹ̀, léraléra ni wọ́n ó…
1 Ẹni tí à ń báwí tí ó ń ṣoríkunkun, yóo parun lójijì láìsí àtúnṣe. 2 Nígbà tí olódodo bá di eniyan pataki, àwọn eniyan a máa yọ̀, ṣugbọn nígbà…
Àwọn Ọ̀rọ̀ tí Aguri sọ 1 Ọ̀rọ̀ Aguri, ọmọ Jake ará Masa nìyí: Ọkunrin yìí sọ fún Itieli ati Ukali pé, 2 “Nítòótọ́ mo jẹ́ aláìmọ̀kan jùlọ ninu gbogbo eniyan,…
Ìmọ̀ràn fún Ọba 1 Èyí ni ọ̀rọ̀ Lemueli, ọba Masa, tí ìyá rẹ̀ kọ́ ọ: 2 Ìwọ ni ọmọ mi, ọmọ bíbí inú mi, ìwọ ni ọmọ tí mo jẹ́jẹ̀ẹ́…
Asán Ni Ilé Ayé 1 Ọ̀rọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n, ọmọ Dafidi, Ọba Jerusalẹmu nìyí. 2 Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. 3 Èrè kí…