ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2

1 Mo wí ninu ọkàn mi pé, n óo dán ìgbádùn wò; n óo gbádùn ara mi, ṣugbọn, èyí pàápàá, asán ni. 2 Mo ní, “Ẹ̀rín rínrín dàbí ìwà wèrè,…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 3

Ohun Gbogbo ni Ó ní Àkókò Tirẹ̀ 1 Gbogbo nǹkan láyé yìí ló ní àkókò ati ìgbà tirẹ̀: 2 àkókò bíbí wà, àkókò kíkú sì wà; àkókò gbígbìn wà, àkókò…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4

1 Mo tún rí i bí àwọn eniyan tí ń ni ẹlòmíràn lára láyé. Wò ó! Omi ń bọ́ lójú àwọn tí à ń ni lára, Kò sì sí ẹnìkan…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 5

Ronú Wò Kí O tó Ṣèlérí 1 Ṣọ́ra, nígbà tí o bá lọ sí ilé Ọlọrun, ó sàn kí o lọ máa kẹ́kọ̀ọ́ níbẹ̀ ju pé kí o lọ máa…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 6

1 Mo tún rí nǹkankan tí ó burú nílé ayé. Ó sì wọ ọmọ eniyan lọ́rùn pupọ. 2 Ẹni tí Ọlọrun fún ní ọrọ̀, ohun ìní ati iyì, tí ó…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7

Èrò nípa Ìgbé-Ayé 1 Orúkọ rere dára ju òróró olówó iyebíye lọ, ọjọ́ ikú sì dára ju ọjọ́ ìbí lọ. 2 Ó dára láti lọ sí ilé àwọn tí ń…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8

1 Ta ló dàbí ọlọ́gbọ́n? Ta ló sì mọ ìtumọ̀ nǹkan? Ọgbọ́n ní ń mú kí ojú ọlọ́gbọ́n máa dán, á mú kí ó tújúká kí ó gbàgbé ìṣòro. Gbọ́ràn…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9

1 Gbogbo nǹkan wọnyi ni mo fi sọ́kàn. Mo yẹ gbogbo rẹ̀ wò, bí ó ti jẹ́ pé ọwọ́ Ọlọrun ni àwọn olódodo, àwọn ọlọ́gbọ́n, ati gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ wọn…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10

1 Bí òkú eṣinṣin ṣe lè ba òórùn turari jẹ́; bẹ́ẹ̀ ni ìwà òmùgọ̀ kékeré lè ba ọgbọ́n ńlá ati iyì jẹ́. 2 Ọkàn ọlọ́gbọ́n eniyan a máa darí rẹ̀…

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11

Nǹkan Tí Ọlọ́gbọ́n Eniyan Ń Ṣe 1 Gbin nǹkan ọ̀gbìn káàkiri lọpọlọpọ, o óo sì kórè ọpọlọpọ èso nígbà tó bá yá. 2 Gbin àwọn kan síhìn-ín, gbin àwọn kan…